Jump to content

Jimmy Odukoya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jimmy Odukoya
Ọjọ́ìbíOluwajimi Odukoya
27 Oṣù Kẹrin 1987 (1987-04-27) (ọmọ ọdún 37)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaOral Roberts University
Iṣẹ́Actor, motivational speaker, preacher, musician
Ìgbà iṣẹ́2016–present
Notable work
Àwọn ọmọ2
Parent(s)

Oluwajimi Odukoya (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1987) jẹ́ òṣèrẹ́kùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàjìríà, àti Olùṣọ́-àgùntàn ìjọ Fountain of Life Church, ní Ilupeju, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn Oba Ade nínú fíìmù The Woman King ti ọdún 2022, pẹ̀lú Viola Davis àti John Boyega.[1][2] Odukoya ní ọmọkùnrin àkọ́kọ́ àti ọmọ kejì Bimbo Odukoya àti Taiwo Odukoya tí wọ́n fìgbà kan jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run, àmọ́ tí wọ́n ti di olóògbé báyìí. Lẹ́yìn ikú bàbá rẹ̀, ó di olùṣọ́-àgùntàn ìjọ Fountain of Life Church, pẹ̀lú ẹ̀gbọ́nbìnrin rẹ̀, ìyẹn Tolu Odukoya-Ijogun gẹ́gẹ́ bí i igbá-kejì Olùṣọ́-àgùntàn. Oṣù kẹsàn-án ọdún 2023 ni àwọn méjèèjì bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àkóso ilé-ìjọsìn náà.[3]

Àtọ́jọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Husbands of Lagos (2016) bíi Fred
  • Tempted (2017) bíi Mike
  • Ordinary People (2017) bíi Andrew
  • Baby Palaver (2018)[4]
  • Cooked Up Love (2018) bíi Abbey
  • The Bosslady (2019) bíi Mike
  • The Bling Lagosians (2019) bíi George
  • Faded Lines (2020) bíi Femi
  • Daydream (2020) bíi Ethan
  • The Wait (2021) bíi Akin
  • Crazy Grannies (2021) bíi Adam
  • Mamba's Diamond (2021) bíi Jay
  • I am Nazzy (2022)[5]
  • The Woman King (2022) bíi Oba Ade
  • Baby Bump (2022) bíi Esosa
  • A Ride Too Far (2023) bíi Jide
  • Broken Mirror (2023) bíi Emma
  • Lock 'N Keys (2023) bíi Johnny
  • Safe (2024) bíi Big D

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Kroll, Justin (9 November 2021). "TriStar's Woman King Starring Viola Davis Adds Four Including Angelique Kidjo". Deadline Hollywood. Archived from the original on November 9, 2021. Retrieved 11 October 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Husseini, Shaibu (13 November 2021). "Jimmy Odukoya: Homeboy earns worthy Hollywood call up". The Guardian Life (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 11 October 2022. 
  3. Apanpa, Olaniyi (2023-09-17). "Meet Nollywood actor, Jimmy Odukoya, now Senior Pastor Fountain of Life Church". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-17. 
  4. Eboseremen, Bartholomew (10 September 2018). "Baby Palaver Review". Nollywood Reinvented. Retrieved 11 October 2022. 
  5. Stephen, Onu (30 April 2022). "Movie Review: I am Nazzy, falls below benchmark". Premium Times. Retrieved 11 October 2022.