Taiwo Odukoya

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taiwo Odukoya

Daniel Taiwo Odukoya (15 June 1956 – 7 August 2023) jẹ́ àlùfáà tí pentecostal ni Nàìjíríà.[1] ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òlùdásílẹ̀ àti àlùfáà àgbà tí The Fountain of Life Church, tí ó si wà ní Ilupeju, Lagos, àti pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ tótó Egbarin ènìyàn ní ọdún 2010s.[2]

Taiwo Odukoya wọn bí ní ọjọ́ Kàrúndínlógún oṣù Kẹfà ọdún 1956 ní ìlú Kaduna, Colonial Nigeria, níbi tí o tún ti dàgbà. Ó kẹko ní ilé ẹ̀kọ́ àlákọ̀bẹ̀rẹ̀ àti gírámà ni Baptist Primary School, Kigo Road, Kaduna àti St. Paul’s College (èyí tí a mọ sí Kufena College, Wusasa) Zaria, lẹ́yìn ìgbà tó wá lọ sí fasiti Ibadan ní ọdún 1976 níbi to tí gba oyè ní petroleum engineering ní ọdún 1981. Gẹgẹbi ẹlẹrọ epo, ó bẹrẹ iṣẹ ni Ile-iṣẹ Epo ilẹ Naijiria (NNPC) ní Oṣù Kẹrin ọdún 1982 Lẹ́hìn ètò kàn ń pá tí National Youth Service Corp (NYSC) fún ọdún kan, o si ṣiṣẹ́ níbẹ̀ títí di àkókò ìfẹhìntì atinúwá rẹ̀ ni Oṣù Kínní ọdún 1994 Lẹ́hìn ìpè sí iṣẹ ìránṣẹ́ rẹ.

  1. "Pastor Taiwo Odukoya's Wife Set to Deliver.". Archived on 7 April 2014. Error: If you specify |archivedate=, you must also specify |archiveurl=. https://www.thenationonlineng.net/2011/index.php/society/29334-pastor-taiwo-odukoya-s-wife-set-to-deliver.html. 
  2. Empty citation (help)