Jump to content

Jimoh Ojugbele

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Jimoh Ojugbele je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba àpapọ̀, tó ń ṣojú Ado-Odo /Ota ti ìpínlè Ogun ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin orílẹ̀-èdè kẹsàn-án. [1] [2]