John Augustus Otunba Payne
Àwọn Lọ́ọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Yorùbá. A kọ ọdún tí wọ́n di looya sí òkè orúkọ wọn
Christopher Alexander Sapara Williams
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1880
Christopher Alexander Sapará Williams
Òun ni ọmọ Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di Lọ́ọ́yà
Rotimi Olusola Alade
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di loya ni 1892
John Augustus Otunba Payne
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1900
E.J. Alexander Taylor
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1905
John Akinola Otunba Payne
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1909
Sir Adeyemo Alakija
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1910
Olayinka Alakija
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1913 Ọláyímíká Alákijà
E.A. Franklin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya n 1921 E. A Franklin
Adedapo Kayode
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1922
Ayodele Williams
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1923
[Ayọ̀délé Williams ]]
C.A. Harrison Obafemi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1924
Rufus Adékúnlé Wright
F.O. Lucas
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1925
Albert Horatus Akíntúndé Doherty
J. Omoniyi Coker
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1926
T.Ekundayo Kusimo Sorinola
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1927
Samuel Ayodele Thomas
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1928
Omosanya Adefolu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1929
Hezekiah Ajayi Johnson (Alias Onibuwe)
Abiola Akinwumi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1930
Ogunyemi Ebikunle Ajose
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O di looya ni 1931
O di looya ni 1933
O di looya ni 1934
O di looya ni 1935
O di looya ni 1936
Won di looya ni 1940
Won di looya ni 1941
Won di looya ni 1942
[[Ọdúnbákú ]]
O di looya ni 1944
Won di looya ni 1946
Won di looya ni 1947
Won di looya ni 1948
[O. Akínkúgbé ]]
Won di looya ni 1949
Won di looya ni 1950
A.G.O. Agbaje
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1952
O. Ajose-Adeogun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1953
[Adéníran Ògúnsànyà ]]
[A.R. Bákàrè]]
O.B. Akin Olugbade
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1954
[Kẹ́hìndé Ṣófọlá ]]
B.O. Babalakin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Won di looya ni 1959
Looya akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Williams Alexander Sapara Williams. Ó di agbẹjọ́rò ní odún 1880.
Magistrate akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọ Yorùbá nì Májísíréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Sir Olumuyiwa Jibalaru. Ọdún 1938 ni ó di Majísíréètì yìí.
High Court Judge akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sir Olumuyiwa Jibalaru ni ọmọ Nàìjíríà kìíní tí yoo di adájọ́ ilé-ẹjọ́ kóòtù gíga (High Court of Judge).
Chief Justice akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò di ‘Chief Justice’ ilẹ̀ Nàìjíríà ni Sir Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá. Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ-ọba Abẹ́òkúta ni.
Senior Advocate of Nigeria (SAN) akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lọ́yà tí ó kọ́kọ́ gba ‘Senior Advocate of Nàìjíríà ‘Chief F.R.A. Williams. Ọmọ Yorùbá ni.
Looya obinrin akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lọ́yà obìnrìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
High Court Judge obinrin akoko ni ile Naijiria
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lọ́yà obìnrìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
link title Archived 2007-08-07 at the Wayback Machine.