John Kerry
Appearance
John Kerry | |
---|---|
68k Aṣàkóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga February 1, 2013 | |
Ààrẹ | Barack Obama |
Deputy | William Joseph Burns |
Asíwájú | Hillary Rodham Clinton |
United States Senator from Massachusetts | |
In office January 3, 1985 – February 1, 2013 | |
Asíwájú | Paul Tsongas |
Arọ́pò | Mo Cowan |
Alága Ìgbìmọ̀ Ilé Alàgbà Aṣòfin fún Ìbáṣepọ̀ Òkèrè | |
In office January 6, 2009 – February 1, 2013 | |
Asíwájú | Joe Biden |
Arọ́pò | Bob Menendez |
Chairman of the Senate Committee on Small Business and Entrepreneurship | |
In office January 4, 2007 – January 3, 2009 | |
Asíwájú | Olympia Snowe |
Arọ́pò | Mary Landrieu |
In office June 6, 2001 – January 3, 2003 | |
Asíwájú | Kit Bond |
Arọ́pò | Olympia Snowe |
In office January 3, 2001 – January 20, 2001 | |
Asíwájú | Kit Bond |
Arọ́pò | Kit Bond |
66th Lieutenant Governor of Massachusetts | |
In office March 6, 1983 – January 2, 1985 | |
Gómìnà | Michael Dukakis |
Asíwájú | Thomas O'Neill |
Arọ́pò | Evelyn Murphy |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | John Forbes Kerry 11 Oṣù Kejìlá 1943 Aurora, Colorado, U.S. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Julia Thorne (1970–1988) Teresa Heinz (1995–present) |
Àwọn ọmọ | Alexandra Vanessa John (Stepson) André (Stepson) Christopher (Stepson) |
Alma mater | Yale University Boston College |
Awards | Silver Star Bronze Star Medal Purple Heart (3) |
Signature | |
Website | http://state.gov/secretary |
Military service | |
Allegiance | United States of America |
Branch/service | United States Navy |
Years of service | 1966–1978 |
Rank | Lieutenant |
Unit | Àdàkọ:USS Coastal Squadron 1 |
Commands | PCF-44 PCF-94 |
Battles/wars | Vietnam War |
John Forbes Kerry (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù Kejìlá ọdún 1944) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà òun ni akọ̀wé-àgbà alákòóso àwọn orílẹ̀-èdè lọ́wọ́́lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè náà tí wọ́n ń pè ní Alákòóso Ọ̀rọ̀ òkèrè Orílè-èdè Amẹ́ríkà68k. Ó ti fìgbà kan jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin-àgbà ti orílẹ̀ èdè náà Aṣòfin àgbà Asofin Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lati Massachusetts lọ́dún 1985 títí di ọdún 2013.[1] [2] [3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Name, Senator (2019-07-12). "U.S. Senate: U.S. Senate Roll Call Votes 107th Congress". 2nd Session. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "KERRY, John Forbes". Biographical Information. 1943-12-11. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "CBS News - Kerry's World: Father Knows Best - March 2, 2004 17:10:22". cbsnews.com. 2004-03-05. Archived from the original on 2004-03-05. Retrieved 2019-12-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Manuscripts and Archives Digital Images Database (MADID)". images.library.yale.edu. Archived from the original on 2013-05-15. Retrieved 2019-12-09.