Jump to content

Joe Biden

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joe Biden
46th President of the United States
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 20 2021
AsíwájúDonald Trump
United States Senator
from Delaware
In office
January 3, 1973 – January 15, 2009
AsíwájúCaleb Boggs
Arọ́pòTed Kaufman
Chairman of the Senate Committee on the Judiciary
In office
January 6, 1987 – January 3, 1995
AsíwájúStrom Thurmond
Arọ́pòOrrin Hatch
Chairman of the International Narcotics Control Caucus
In office
January 4, 2007 – January 3, 2009
AsíwájúChuck Grassley
Arọ́pòDianne Feinstein
Chairman of the Senate Committee on Foreign Relations
In office
January 4, 2007 – January 3, 2009
AsíwájúRichard Lugar
Arọ́pòJohn Kerry
In office
June 6, 2001 – January 3, 2003
AsíwájúJesse Helms
Arọ́pòRichard Lugar
In office
January 3, 2001 – January 20, 2001
AsíwájúJesse Helms
Arọ́pòJesse Helms
Member of the New Castle County Council
In office
1970 – 1972
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí20 Oṣù Kọkànlá 1942 (1942-11-20) (ọmọ ọdún 81)
Scranton, Pennsylvania
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Neilia Hunter (deceased; m. 1966 – 1972)
Jill Jacobs (m. 1977)
Àwọn ọmọBeau Biden
Robert Hunter Biden
Naomi Christina Biden
Ashley Blazer Biden
ResidenceNumber One Observatory Circle (Official)
Wilmington, Delaware (Private)
Alma materUniversity of Delaware (B.A.)
Syracuse University College of Law (J.D.)
ProfessionLawyer
Signature
Websitehttps://whitehouse.gov/administration/president-biden/

Joseph Robinette Biden Jr.(tí a bí ní November 20, 1942)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Amerika àti Ààrẹ Amẹ́ríkà lọ́wọ́ lọ́wọ́. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú "Democratic Party". Óun ni ìgbàkejì ààrẹ orílè-èdè Amerika láàrin ọdún 2009 sí 2017 lábé isejoba Ààrẹ Barack Obama, òun sì ni Senato tí ó ṣe asoju Delaware láàrin ọdún 1973 sí ọdún 2009.

Wọ́n bi sí Scranton, Pennsylvania, ó sì padà kó lọ Delaware ní ọdun 1953. Ó kàwé ní Yunifásitì ti Delaware kí ó tó tesiwaju ní Yunifásitì Syracuse láti gbami eye ìmò òfin.  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named lat082408nw
  2. "Joe Biden - Age, Bio, Birthday, Family, Net Worth". National Today. October 17, 2022. Retrieved January 5, 2023.