Calvin Coolidge
Ìrísí
Calvin Coolidge (John Calvin Coolidge Jr.;[1] /ˈkuːlᵻdʒ/; tí a bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù keje ọdún 1872 àti tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ Kàrún oṣù Kínní ọdún 1933) jẹ́ jẹ́ agbejọ́rò àti olọ́sẹ̀lú ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Òun ní Ààrẹ Ọgbọ́n láti gun orí àléfà Amerika, ó jé Ààrẹ láti ọdún 1923 di 1929.
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "John Coolidge, Guardian of President's Legacy. Dies at 93". The New York Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). June 4, 2000. Retrieved May 11, 2019.
[He] had originally been John Calvin Coolidge, but dropped his first name to avoid confusion and later legally changed it.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |