Jump to content

Johnson Akin Atere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Johnson Akin Atere [1] jẹ bíṣọ́ọ́bù Anglican ní Nàìjíríà: [2]. Òhun ni ó jẹ́ bíṣọ́ọ́bù lọ́wọ́ lọ́wọ́ ní Awori. [3]

A bí Akin Atẹ́rẹ́ ní ọdún 1956 ní Àkókó, Ìwọ-Gúsù, Ìpínlẹ̀ Òndó. Ó kọ́ṣẹ́ ó sì ṣiṣẹ́ olùkọ́ kí ó tọ wọ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìmọ̀ Bíbélì Olùkọ́ni Gíga ti Immanuel ní Ìlú Ìbàdàn ní ọdún 1985. O di ìránṣẹ́ tí a yàn ní ọdún 1988, ó sì sìn ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Ilasamaja, Sángo-Ọ̀tà àti Surulere. Ó jẹ́ kánọ́ọ́nì tí wọn fẹ́ràn jùlọ ní ọdún 1999 àti díákónì tí ó ga jùlọ ni ọdún 2002. Òhun ni ó jẹ́ olùkọ́ àgbà nínú Ẹ̀kọ́ Májẹ̀mú Láíláí ni Ilé Ẹ̀kọ́ Olùkọ́ni Àgbà tí Ìmọ̀ Bíbélì tí Àgbà Bíṣọ́ọ́bù Vining títí ìsìn ìyàsímímọ́ rẹ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní tí ọdún 2009. Ó gba Ph.D. láti Ilé Ìwé Gíga ti Ìpínlẹ̀ Èkó.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Anglican Communion
  2. LinkedIn
  3. "Diocesan web site". Archived from the original on 2024-09-13. Retrieved 2024-08-28.