Jude Idada
Jude Idada jẹ́ òǹkọ̀wé àti òṣèré ni Nigeria tí ó gbajúmọ̀ fún eré tí ó ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀' The Tenant.[1] Ó sì ti kọ àwọn eré àgbéléwo kékèèke àti àwọn ìro òmíràn.[citation needed]
Igba Èwe àti Ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Idada, láti ìran àwọn Edo, wọ́n bíi sí Lagos, Nigeria, níbẹ̀ ni ó sì dàgbà si.[2]Idada jẹ́ onímọ sáyẹ́ǹsì pọ́ńbélé láì ní ìmọ̀ nínu ẹ̀ka ti iṣẹ́-ọnà kankan nígbàtí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ girama. Èto ìṣègun-òyìnbó ni ó kọ́kọ́ fẹ́ kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ṣùgbọ́n ó padà mú ẹ̀kọ ìdáko ati èto ọrọ̀ ajé. Lẹ́yìn tí ó ṣe táàmù kán, Idada fi ẹ̀kọ́ sílẹ̀, tí ó sì dúró ní ilé fún oṣu mẹsan, lẹ́yin náà ni ó lọ sí tí ó kọ́ eré ìtàgé, University of Ibadan níbẹ̀ sì ni ó ti gba ìwé ẹ̀ri àkọ́kọ́ ti ilé-ìwé gíga.[3][4]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè,Idada ṣiṣẹ́ ní Guardian Express Bank, iṣẹ́ tí ó gbà nígbàti ó wà bíi corps member lẹ́yìn èyítí ó lọ sí Arthur Andersen. O ṣíkọ̀ lọ sí Canada, ó gba ìwe-ẹ̀ri kejì ó sì bẹ̀rè sí ní ṣiṣẹ́ ní oríṣiríṣi báankì, ilé-iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ àti àwọn iṣẹ́ tí ó jọ mọ́ ọ. Lẹ́yìn tí ó wo àwọn fíìmù kan pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ rẹ̀, ó kọ̀wé fi iṣẹ́ sílẹ̀ láti bẹ̀rẹ ìwé kíkọ àti fíìmu ṣíṣe.[5][6]
Wọ́n yàn-án gẹ́gẹ́ bíi akọ̀wé fun Toronto International Film Festival àti Afrinolly/Ford Foundation ti Sinimá. Idada kópa nínu ìṣère àkọ́kọ́ ní Relativity Media/AFRIFF .
- ↑ Agary, Kaine. "Getting from script to screen and the rights in-between". Punch. http://punchng.com/getting-script-screen-rights/. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ "Jude Idada". IMDb. https://www.imdb.com/name/nm3338983/?ref_=nmbio_bio_nm. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ "Interview with award winning Director". FAB. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ "Jide Idada". Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ "Interview with award winning Director". FAB. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ "Jide Idada". Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 17 January 2017.
Fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Chameleon (Short Film) – 2016 – Writer/Director
- Blaze Up The Ghetto (Documentary) – 2010 – Director
- The Tenant (Feature Film) – 2005 – Writer/Producer
- Inside (Short Film) – 2000 – Director/Producer
- The Woman in my Closet – (Short Film) – 1999 – Director/Producer
- Young Wise Fools – (Short Film) – 1999 – Director/Producer
Eré orí ị̀tàgé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 3some by Idada – 2018 – Director/Producer
- Coma by Idada – 2013 – Director
- Lost by Modupe Olaogun – 2013 – Director
- Brixton Stories by Biyi Bandele – 2012 – Director
- The Flood by Femi Osofisan – 2011 – Director
- In The Name of The Father – 2008 – Writer/Director
- The Seed of Life – 2008 – Writer/Director
- Love is the Word – 2007 – Writer/Director
- Your God is Dead – 2000 – Director/Writer/Producer
- Power of Love – 1999 – Director/Writer/Producer
- Snares of Lucifer – 1998 – Director/Writer/Producer
Ipa míràn tí ó kó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré ìṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Simi (feature film) – 2016 – For Applegazer and Karmacause Productions, producer, Udoka Oyeka
- Tatu (Feature film) – 2016 – For Filmhouse Productions, producer, Don Omope
- The River (feature film) – 2015 – For Applegazer and Karmacause Productions, Producer Orode Uduaghan
- House Girls (TV Series) – 2015 – For Xandria Productions; Producers, Chineze Anyaene, Theophilus Ukpaa.
- Driving Mr Akin (feature film) – 2015 – For Xandra Productions, producer, Chineze Anyaene.
- Doctor Death (feature film) – 2014 – For Raconteur/Creoternity Productions, Producer Chioma Onyenwe
- The Road (Short film) – 2014 – For Afrinolly/Ford Foundation
- Justice (Short film) – 2014 – For Elvina Ibru Productions
- Sunshine (feature film) – 2013
- Coma (Feature Film) – 2012 – For I Take Media, Producers, Fabian Lojede, Mickey Dube
- Journeys of One (Feature Film) – 2011 – For Omcomm Communications, Producer; Soledad Grognett
- Lagos Connection (Feature Film) – 2011 – For 1 Take Media, Producer; Fabian Lojede
- Afreeka (Feature Film) – 2010
- The Drum (Feature Film) – 2010
- Sex in the Age of Innocence (Feature Film) – 2009
- No More An Uncle Tom (Feature Film) – 2009
- The Dilemma (Feature Film) – 2008
- Ghetto Red Hot (Feature Film) – 2007 – (Optioned)
- Mirage (Feature Film) – 2006
- Kite (Feature Film) – 2006 – for NTFG Productions, Producer Yifei Zhang
- The Tenant (Feature Film) – 2005 – released 2008 by Broken Manacles Entertainment
- Somewhere in Between (Feature Film) – 2005 (Optioned)
- Faces of a Coin (Feature Film) – 2004 (Optioned)
- Inside – (Short Film) – 2000
- The Woman in my Closet – (Short Film) – 1999
- Young Wise Fools – (Short Film) – 1999
- Two Faces of a Coin (Short Film) – 1998
Eré orí ìtàgé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Sankara – 2016 – Commissioned by G.R.I.P media
- MKO – 2016 – Commissioned by the MKO Abiola family
- 3some – 2016 – Optioned by Make It Happen Productions
- The March – 2016 – Optioned by Theatre Magnifica
- Resurrection – 2014 – Optioned by Oracles Repertory Theatre
- The Calling – 2013 – Commissioned by African Theatre Ensemble
- Coma – 2012 – Optioned by Oracles Repertory Theatre
- In The Name of The Father – 2008 – Performed by the Visionaries
- The Seed of Life – 2008 – Performed by the Visionaires
- Love is the Word – 2007 – Performed by the Visionaires
- Vendetta – 2006 – Optioned by the Africa Theatre Ensemble
- Oduduwa "King of the Edos" – 2005 – Performed by the Oracle Repertory Theatre
Published by Createspace/Creoternity Books
- Power of Love – 1994 – Performed by Neighbours International
- Your God is Dead – 1994 – Performed by Neighbours International
- Snares of Lucifer – 1993 – Performed by Neighbours International
Ìwé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- More than Comedy (A Biography of Efosa ‘Efex’ Iyamu) – 2015
- Didi Kanu and the Singing Dwarfs of the North – 2015- Createspace/Creoternity Books
- By My Own Hands – 2014 – Createspace/Creoternity Books
- A Box of Chocolates[2] – 2005 – Trafford Publishing (Collection of Short Stories)
- Boom Boom – 2019 – Winepress Publishing
Ewì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Exotica Celestica – 2012 – Createspace/Creoternity Books
- Meditations of a Traveling Mind – 2004
- Oh My Lord! – 1992
Orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Firefly – 2016 – Chibie; Producer: Brian Quaye, Chibie Okoye
- Life is Sweet– 2013 – Chibie; Producer: Jeff McCulloch
- Speed Demon – 2013– Chibie; Producer: Jeff McCulloch
- Revolution – 2013 – Chibie; Producer: Soji Oyinsan
- I No Be Tenant – 2010 – Blacko Blaze ft Chibie; Producer: Blacko Blaze, Released by Broken Manacles Entertainment
Eré ṣíṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 8 Bars and A Clef (Feature Film) – Dir Chioma Onyenwe – 2014
- The Tenant (Feature Film) – Dir Lucky Ejim – 2006
- Death and the Kings Horseman (Stage Play) – Dir Ronald Wiehs – 2004
- The Prize (Stage Play) – Dir Lekan Fagbade – 2000
- Inside (Short Film) – Dir Idada – 2000
- Ezenwanyi (Stage Play) – Dir Chetachukwu Udo – Ukpai – 1999
- The Woman in my Closet (Short Film) – Dir Idada – 1999
- Young Wise Fools ( Short Film) – Dir Idada – 1999
- Doom (Stage Play) – Dir Yacoub Adeleke – 1997
- Grip Am (Stage Play) – Dir Dare Fasasi – 1997
- Hopes of the Living Dead (Stage Play) – Dir Lekan Fagbade – 1998
- Queen Idia (Stage Play) – Dir Israel Eboh −1998
- Human Zoo (Stage Play) – Dir Dare Fasasi – 1997
- Snares of Lucifer (Stage Play) – Dir Idada, Ifeanyi Agu – 1993, 1997
- Your God is Dead (Stage Play) – Dir Idada – 1994
- Power of Love (Stage Play)- Dir Idada – 1994, 1999
- Eku (Stage Play) – Dir Wale Macaulay – 1995
- Atakiti (Stage Play) – Dir Esikinni Olusanyin – 1995
Ẹ̀bùn àti Ìdánimọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Work | Result |
---|---|---|---|---|
2019 | Nigeria Prize for Literature | Children Novel | Boom Boom | Gbàá |
2014 | Nigeria Prize for Literature | Use Of Literature | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
2013 | Association of Nigerian Authors Award | Best Drama | Oduduwa, King of the Edos | Gbàá |
2010 | 6th Africa Movie Academy Awards | Best Picture | The Tenant| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
2010 | 6th Africa Movie Academy Awards | Best Screenplay | Gbàá | |
2010 | 6th Africa Movie Academy Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ . Amazon.com https://www.amazon.com/s/ref=nb_sb_noss/156-3346445-9322156?url=search-alias%3Dstripbooks&field-keywords=+Jude+Idada. Retrieved 19 January 2017. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ Idada, Jude (1 March 2013). A Box of Chocolates. CreateSpace Independent Publishing Platform. ISBN 978-1478125327.
- ↑ . Amazon.com https://www.amazon.com/s/ref=nb_sb_noss/156-3346445-9322156?url=search-alias%3Dstripbooks&field-keywords=+Jude+Idada. Retrieved 19 January 2017. Missing or empty
|title=
(help)