Káábà
Ìrísí
Kaaba | |
---|---|
Location | Mecca, Saudi Arabia |
Branch/tradition | Islam |
Kaaba (Lárúbáwá: الكعبة / DIN 31635: al-Kaʿbah / IPA: [ˈkɑʕbɐ] / English: The Cube)[1] ni ilé kékeré bí Apoti tí ó wà ní Mekka, Saudi Arabia, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ibi mímọ́ jùlọ nínú èsìn Imale.[2] Ilé yí ti wà ṣíwájú èsìn Ìmàle, gẹ́gẹ́ bí ìtàn ẹ̀sìn Islam ti fi lélẹ̀, ilé náà di kíkọ́ síbẹ̀ látọwọ́ òjísẹ́ Ọlọ́run Abraham. Ilé náà ni wọ́n kọ́ mosalasi yíká, Mosalasi Al Haram. Gbogbo àwọn musulumi kákiri ayé ló ma ń kọjú sí Kàábà tí wọ́n bá ń kirun ní yówù tí wọ́n bá wà lágbàáyé.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Also known as al-Kaʿbatu l-Mušarrafah (الكعبة المشرًّفة "The Noble Kaʿbah), al-Baytu l-ʿAtīq (البيت العتيق "The Primordial House"), or al-Baytu l-Ḥarām (البيت الحرام "The Sacred House")
- ↑ Wensinck, A. J; Ka`ba. Encyclopaedia of Islam IV p. 317
Coordinates: 21°25′21″N 39°49′34″E / 21.42250°N 39.82611°E