K1 De Ultimate

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
K1 De Ultimate

 Wọ́n bí Ọlásúnkànmí Wasiu Àyìndé Adéwálé Marshal tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí K1  De Ultimate, ní ọjọ́ kẹta oṣ̀u kẹta ọdún 1957 (March 3, 1957) ní Ìjẹ̀bú Òde ìpínlẹ̀ Ògùn . Ó jẹ́ olórin Fújì ọmọ Nàìjíríà. Ó di gbajú-gbajà olórin nípa bí ó ṣe fi àwọn ohun ìlù ìgbàlódé bíi Ḱibọọdù, sasofóònù àti jìtá kún orin Fújì.[1]

ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wasiu Àyìndé Adéwálẹ́, Ọmọ́gbọ́láhàn, Ọlásúnkànmí Anífowóṣe, K1 De Ultimate tí ó tún jẹ́ ọba orin Fújì ṣe àwárí ìmọ̀ àti ẹ̀bùn orin kíkọ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ. Lóótọ̣́, àwọn òbí rẹ̀ lòdì sí kí ó kọrin nítorí wón gbà wípé olè àti ọ̀lẹ ni ó ń ṣagbe, ṣùgbọ́n ó kọ̀ jálẹ̀ tí ó sì ń bá ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ títí  ó fi di ọmọ ọdún mẹ́èdógún (15 yaers). Fúndìi èyí, ó jáwé olúborí nínú àwọn ìdíje ọlọ́kan ò jọ̀kan abẹle.[2] Lẹ́yìn èyí ni ó dara pọ̀ mọ ọmọ ẹgbẹ́ olórin lẹ́yìn Àyìndé Barrister, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀gá elére Fújì láti ọdún 1975 tí ó sì dá dúró gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá ara rẹ̀ ní ọdún 1978. Àsìkò yìí náà ni ó gbé àwo orin tuntun kan jáde tí ó pè ní "Ìbà Special track" àti  'Àbọ̀dé Mecca' ní ọdún 1980. Lẹ́yìn àwo yìí ni ó tún gbé àwo tí ó sọọ́ di àyànfẹ́ gbogbo àwọn ènìyàn ní 1984 tí ó pè ní Talazo 84.[1]

Ìgbòkègbodò iṣẹ́ orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

K1 De Ultimate bẹrẹ̀ ìrìn àjò jákè-jádò àgbáńlá ayé láti Gúsù Amẹ́ríkà (North America) ní ilẹ̀ Europe ní ọdún 1984, tí ó sì ń rin ìrìn àjò náà títí di òní.[3] Ní ọdún 1996 ó kọ orin Fújì ìtagbangba rẹ̀ àkọ́kọ́ níbi ayẹyẹ WOMAD Festival. Bákan náà ni ó jẹ́ òṣeré Fuji àkọ́kọ́ tí ó tí ó kọ́kọ́ ṣeré ní Troxy, WOMEX àti SOB's.[4]

Àwon awo orin re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • 1980 Ìbà (Tgaines)
 • 1981 Èsì Ọ̀rọ̀ (Tgaines)
 • 1982 Ìgbàlayé (Tgaines)
 • 1984 Talazo System (Tgaines)
 • 1984: Talazo '84
 • 1984: Iṣẹ́ L'Ògùn Ìṣé (Tgaines)
 • 1984 Ijó ọlọ́mọ (Tgaines)
 • 1985: Talazo Disco 85 (Tgaines)
 • 1985 Alhaji Chief Wasiu Ayinde Barrister and His Talazo Fuji Commanders Organisation Olóríkì Méta / Ki De Se [p] Vinyl LP Leader Record / LRC (LP) 05 (Tgaines)
 • 1985: Ẹ lọ-Ṣọra (Tgaines)
 • 1985 Pomposity (Tgaines)
 • 1986 Orí (Tgaines)
 • 1986: Tiwá Dayò (Tgaines)
 • 1986: Erín Gòkè - Lecture (Tgaines)
 • 1986 Baby Jẹ́ Kájó (Tgaines)
 • 1987: Talazo In London (Tgaines)
 • 1987: Aiyé (Tgaines)
 • 1987 Adieu Awólọ́wọ̀ (Tgaines)
 • 1988: Sun - Splash (Tgaines)
 • 1988 Fuji Headline (Tgaines)
 • 1988 My Dear Mother (Tgaines)
 • 1989: Fuji Rapping–– (Tgaines)
 • 1989: Achievement (Tgaines)
 • 1990: Jó Fún Mi (Dance For Me) (Tgaines)
 • 1991: American Tips
 • 1991: Fuji Collections (Tgaines)
 • 1993: The Ultimate (Tgaines)
 • 1994: Consolidation (Tgaines)
 • 1995: Reflection (Tgaines)
 • 1995 Talazo Fuji Party Music Compact Disk (Tgaines)
 • 1996:Legacy (Tgaines)
 • 1996: Faze 2 Global Tour '96 (Tgaines)
 • 1997:History (Edited By Tgaines)
 • 1997 Berlin Compact Disk (Tgaines)
 • 1999:Fuji Fusion (Okofaji Carnival) (Tgaines)
 • 2000: New Era (Tgaines)
 • 2000: Faze 3 (Tgaines)
 • 2001: Message (Tgaines)
 • 2001:Statement (Tgaines)
 • 2001: New Lagos (Tgaines)
 • 2002: Gourd (Tgaines)
 • 2003: Big Deal (Tgaines)
 • 2006: Flavour
 • 2011: Tribute To My Mentor (Tgaines)
 • 2012: Instinct (Tgaines)
 • 2012 Fuji Time (Tgaines)
 • 2017 22 Dec Fuji Ep Let Music Flow (Tgaines)
 • 1983 Talazo System
 • 1984:Omo Akorede
 • 1986: Golden Mercury
 • 1989: Siliky
 • 1990 American Tour Live
 • 1991 Yuppie Night 1 n 2
 • 1994: Consolidation live Ade Bendel
 • 1995 Sabaka Night
 • 1995 Oju Opon
 • 1995 Fadaka Club
 • 1995 London Hamburg Amsterdam Berlin 95
 • 1997 London Hamburg Amsterdam Berlin Paris 97
 • 1998 United Kingdom Live
 • 1998 Newyork Chicago Atlanta Houston & Canada Tour Toronto Montreal live 1998
 • 1999 New Era Live United Kingdom
 • 1999 Afinni
 • 2000 Canada live
 • 2007 United Kingdom Ireland Tour Live
 • 2007 The Truth Live

And Many More Hit Live Eko for show usa 1990 Concert

 • 1995 Womad Concert
 • 1997 Benson & Hedges
 • 1999 Benson & Hedges Loud in Lagos

Àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó ti gbà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. 1.0 1.1 Harris, Craig. "Ayinde King Wasiu Marshal | Biography & History". AllMusic. Retrieved May 29, 2016. 
 2. Paul Wale Ademowo, " ISBN 978-9-78322-089-8, Publisher: Effective Publishers (1996)
 3. http://allafrica.com/stories/201408010118.html
 4. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2018-06-14. Retrieved 2018-05-09.