Karl Jaspers
Appearance
Karl Theodor Jaspers | |
---|---|
Karl Jaspers | |
Orúkọ | Karl Theodor Jaspers |
Ìbí | Oldenburg, Grand Duchy of Oldenburg, Germany | Oṣù Kejì 23, 1883
Aláìsí | February 26, 1969 Basel, Switzerland | (ọmọ ọdún 86)
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Existentialism, Neo-Kantianism |
Ìjẹlógún gangan | Psychiatry, Theology, Philosophy of History |
Àròwá pàtàkì | Axial Age, coined the term Existenzphilosophie, Dasein and Existenz |
Ìpa lórí
|
Karl Theodor Jaspers (February 23, 1883 – February 26, 1969) je asewosan-emin ati amoye ara Jemani to ko ipa gidi lori oro-olorun odeoni. Leyin to ko eko nipa bi a ti n se iwosan-emin, Jaspers boju de iwadi imoye, o si tiraka lati wa sistemu imoye tuntun. O je gbigba bi akede iseoniwalaaye ni Jemani, botilejepe ko faramo pipe be.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |