Jump to content

Kehinde Kamson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kehinde Kamson
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹjọ 1961 (1961-08-14) (ọmọ ọdún 63)
ìpínlè Èkó, Nàìjíríà
Ẹ̀kọ́Bachelor's Degree in Accounting
Iléẹ̀kọ́ gígaQueens College Lagos

Yunifásítì ìpínlè Èkó

Lagos Business School

Kehinde Kamson, tí àwọn mìíràn mọ̀ sí KJW(a bi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ ọdun 1961 ni Ipinle Eko, Naijiria) je onisowo ati olufini omo Naijiria. Oun ni oludasile ati oludari ilé-isé Sweet Sensation Confectionery Limited,[1] ilé-isé náà jé okan lara a won ilé-isé to ún se ounje atete se(fast food). Samson bèrè ilé-isé náà leyinkule re ko to dipe ilé-isé náà di gbajumo.

Àárò ayé àti Èkó rè

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Kehinde sinu idile Adeleke Beniah Adelaja(Baba re) ati Omoba Adebayo Evengelin Adelaja(Iya re). Baba re, Adeleke Beniaj Adelaja je okan lara awon gbajumo adari ilé-ìwé CMS grmmer school - grammer school ti akoko dálè ni Nàìjirià. Iya re je adari Eva Adelaja Secondary School ni ìpínlè Eko.[2] Iya re tun je onisowo. Kehinde ati ibeji re jé abikeyin Baba ati Iya won ninu omo mefa. O lo ilé-ìwé International women's society Nursery school fún iwe akobere ko to lo Staff school ti Yunifasiti eeko fun Eko primari re, o ka ìwé sekondiri ní ilé-ìwé St. Aness School, ìlú Ibadan. Ìgbà tí o wa ní ilé-ìwé Sekondiri ni ayán láti se asoju ilé-ìwé rè ni eré idaraya All African Games, o jawe olubori ninú àwon idije titi o fi se asoju Iwọ-oorun Afrika. O gba àmì-èye goldu(wúrà) nitoripe o se asoju Iwọ-oorun Afrika ninú eré idaraya ti Table Tennis bi o tile jé wipe o fìdíremi. O gba àmì-èye Bachelor Degree nínú ìsirò láti Yunifásitì ìlú Eko, Nàìjíríà [3] O tún pada lo ilé-ìwé Isowo ti Eko.

  1. Ashefon, Kemi (2021-09-24). "I Feel Like A Gal At 60—Kehinde Kamson, Founder, Sweet Sensation (Lovehaven Magazine, September Issue)". Kemi Ashefon Love Haven. Retrieved 2022-05-30. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "How This Female African Entrepreneur Built A Million Dollar Business From A Small Shed". StartupTipsDaily. 2019-07-17. Retrieved 2022-05-30. 
  3. "I Got Into The Food Business Accidentally – Founder/CEO, Sweet Sensation, KEHINDE KAMSON". City People Magazine. 2020-07-07. Retrieved 2022-05-30.