Kelvin Katey Carboo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kelvin Katey Carboo tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù kẹta (Oṣù Ẹrẹ́nà), ọdún 2000. Ó jẹ́ eléré ìdárayá bọ́ọlù àláfọwọ́gbá (Volleyball) tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Ghana. [1][2][3][4].

Ìgbèsi ayè ati iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Carboo ní ìlú Accra, ní orílẹ̀-èdè Ghana. Ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta (Oṣù Ẹrẹ́nà), ọdún 2000. Carboo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gégẹ́ bíi eléré-ìdárayá volleyball ní ọdún 2017, nígbà tí ó kopa nínú eré volleyball àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ nínú ìdíje Commonwealth pẹ̀lú Akin ẹgbé rẹ̀ Eric Tsatsu, tí wọ́n sì gbé ipò kẹrin nínú ìdíje náà.[5] Ni óṣu keje, ọdun 2018 elere naa kopa ninu ere awon ọdọ ilẹ afirica to waye ni ilẹ Algeria[6][7]. Ni óṣu kẹfà , ọdun 2019 Arakunrin naa kopa ninu ere eti odo akọkọ ilẹ afirica pẹlu Akin ẹgbẹ rẹ Essilfie Samuel Tetteh ti wọn si gba ipó kèji[8]. Ni óṣu kini,ọdun 2020 elere naa kopa ninu ìfe tí CAVB (CAVB Cup) ni ilẹ Accra pẹlu Akin ẹgbẹ rẹ Essilfie nibi ti wọn ti gbègba órokè ṣe ipó akọkọ[2].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://en.volleyballworld.com/en/beachvolleyball/worldtour/2019/msal19/men/teams/948046-carboo-essilfie/kelvin_katey_carboo?id=164390
  2. 2.0 2.1 https://en.volleyballworld.com/en/beachvolleyball/worldtour/2020/myog2018/men/teams/939831-carboo-tsatsu/kelvin_katey_carboo?id=164390
  3. http://www.bvbinfo.com/player.asp?ID=19036
  4. https://www.olympedia.org/athletes/2503122
  5. https://www.modernghana.com/sports/788491/goc-president-inspires-young-athletes-for-2017.html
  6. https://www.globaltalent.pro/info/user/kelvicarbo23400/
  7. https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/SportsArchive/Abeiku-Jackson-captains-team-Ghana-for-2018-Africa-Youth-Games-669537
  8. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-01. Retrieved 2023-03-11.