Kenneth Okolie
Kenneth Okolie | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Kenneth Obinna Okolie 21 Oṣù Kejì 1984 Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Valley View University[1][2] |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2006-Present |
Height | ruben aguirre is 6’7” |
Kenneth Obinna Okolie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹjọ ọdún 1984, jé òṣèré orí-ìtàgé, módẹ́ẹ̀lì tí ó sì ti fìgbà kan jẹ́ Ọ̀gbẹ́ni Nàìjíríà nígbà kan rí látàrí ipa rẹ̀ nínú iṣẹ́ módẹ́ẹ̀lì ní ọdún 2010. [4] O tún gba àmì-ẹ̀yẹ tí ayẹyẹ City People Entertainment Awards gẹ́gẹ́ bí Òṣéré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó pérégedé jùlọ ní ọdún 2015[5][6][7]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okolie jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ihiala ní Ìpínlẹ̀ Anambra. Òun ni ó jẹ́ àkọ́bí àti àkọ́já ewé àwọn òbí rẹ̀. Ó kàwé jáde nílé ẹ̀kọ́ Valley View University ní orílẹ̀-èdè Gánà.[8][9]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Òṣèré àti Módẹ́ẹ̀lì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ṣáájú kí Okolie tó di ìlú-mọ̀ọ́ká nínu ilé-iṣẹ́ Nollywood, ó ti bẹ̀rẹ̀ bí Módẹ́ẹ̀lì.[10]ní ọdún 2006. O se alaye wipe sise Módẹ́ẹ̀lì kìí ṣe ohun tí ó wù òun láti ọkàn wá nítorí wípé òun sin ọ̀rẹ́ òun kan lọ sí ibùdó ìfihàn náà ni kí wọ́n tó fi iṣẹ́ náà lọ òun tí òun sì gbà làti ṣiṣẹ́ náà. Òun yege nínú ìfihàn náà tí wọ́n sì yan òun láti kópa nínú ìdíje ní ọdún 2006. Ní ọdún 2010, Ó tún kópa nínú ìdìje tí ó mu gba àmì-ẹ̀yẹ Ògbéni Nàìjíríà.[11][12] Okolie tún kópa nínú ìfihàn Ọkùnrin tí ó dára jùlọ ní àgbàyé, tí ó sì gba ipò kejì. Ó tún dara pọ̀ mọ́ wọn àwọn òṣèré orí-ìtàgé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2011.[13][14]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okolie gba àmì-èyẹ ti City People Entertainment Awards fùn Òṣèrékùnrin amúgbálẹ́gbẹ́ tí ó peregedé jùlọ.[15][16]
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okolie śe ìgbèyáwó pẹ̀lú arábìnrin Nwaka Jessica ní ọdún 2017, wọ́n sì bímọ ní ọdún 2019.[17][18][19]
Ìjínigbé ti ọdún 2012
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okolie rin ìrìn-àjò lọ sí ìlú Owerri tí ó jẹ́ olú-ìlú fún Ìpínlẹ̀ Imo láti lọ ya sinimá kan pẹ̀lú àwọn òṣèré akẹgbẹ́ rè kan Nkiru Sylvanus. Wọn fi léde wípé àwọ́n ajínigbé jí Okolie àti Nkiru Sylvanus gbé ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Kejìlá, tí wọ́n sì ń bèrè fún ọgọ́rùn ùn mílíọ̣́nù (₦100,000,000) kí wọ́n tó fi àwọn òṣèré méjèèjì yí sílẹ̀.[20][21] Àwọn ajínigbé náà dá Okolie àti ẹnìkejì rẹ̀ Nkiru Sylvanus sílè lẹ́yìn ọjọ́ kẹfà tí wọ́n ti jí wọn gbé ní déédé agogo mẹ́wàá àbọ̀ alẹ́. Àmọ́ iye tí àwọn ajínigbé náà gbà kí wọ́n tó dá wọn sílẹ̀ kò hàn sí ẹnìkẹ́ni.[22][23][24][25]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]N° | Àkọ́lé eré | Ọdún | Ipa tí ó kó |
---|---|---|---|
1 | Aina | 2011 | Bako |
2 | Keeping My Man | 2013 | |
3 | House Husband | 2015 | Chude |
4 | Gbomo Gbomo Express | (2015)[26] | |
5 | 25th Birthday | 2016 | Melvin |
6 | My Name is Kadi | 2016 | |
7 | Trouble Comes To Town | 2016 | Benny |
8 | A Girl’s Note | 2016 | Ken |
9 | Evol | 2017 | Kamari |
10 | Strangers | 2017 | Reginald |
11 | Mystified | 2017 | Teddy |
12 | Stormy Hearts | 2017 | |
13 | Next Door | 2017 | |
14 | The Royal Hibiscus Hotel | 2017 | Deji[27][28] |
15 | Different Worlds | 2019 | Ike |
16 | Molly’s Love Story | Tony | |
17 | Black Coffee | Francis Adu | |
18 | Reaction | 2019 | Desmond |
19 | Snap | 2019 | Jerry |
20 | Mr & Mrs ABAKOBA | Ifeanyi | |
21 | Drifted( When a soldier loves) | Ola | |
22 | Just a wish | Dave | |
23 | A Friendly Fire | Daniel | |
24 | Royal Tussle | ||
25 | This is not a love story | Kolawolé | |
26 | Borrowed Heart | ||
27 | Dear Ijeoma | Nicolas | |
28 | Hit and Run | ||
29 | A toast to a heart break | Michael | |
30 | Tripod | ||
31 | A long walk to nothing | ||
32 | 3 some | ||
33 | Reconciliation | ||
34 | My Silence | ||
35 | Stranger than ever | ||
36 | No strings attached | ||
37 | Wedlock | ||
38 | Bride with Gun | ||
39 | Lunch Times Heroes | ||
40 | Espionage | ||
41 | Kazbar | ||
42 | Date Night | ||
43 | A haunted Marriage | ||
44 | Open Scars | ||
45 | Ruth | ||
46 | One Bite | ||
47 | The Sassy One | Scott | |
48 | Promises are forever | Dan | |
49 | Deluded | ||
50 | Love isn't enough | ||
51 | The Cleansers | 2020 | |
52 | Stroke ok luck | 2020 | |
53 | The tea Room | ||
54 | A tiny line | ||
55 | Olive | ||
56 | Izunna | ||
57 | Rising Above | ||
58 | Oath of silence | ||
59 | Heart Ripper | ||
60 | Love and Shadow | ||
61 | Strength of love | ||
62 | Imperfect Me | ||
63 | Crumbles cookies | ||
64 | Fatal Attraction | ||
65 | The right kind of wrong | ||
66 | Jumbled | 2019 | Damilola |
67 | Mothers and daughters in law | ||
68 | Don't get mad Get Even | ||
69 | Mr Black | ||
70 | RIFT | ||
71 | Lovers or Loosers (LOL) | ||
72 | Ignition | ||
73 | Chances | ||
74 | Ufuoma | ||
75 | True vows | ||
76 | The department | ||
77 | Rubbles of love | ||
78 | Just 2 hoours | ||
79 | A Girl's Note | ||
80 | Alera's Diary | ||
81 | PayBack |
TV Shows
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]N° | TV Series Title | Year | Character | Seasons |
---|---|---|---|---|
1 | Desperate House Girls | 2013 | 1-2 | |
2 | Husbands of Lagos | 2015 | Akinlolu | 1-2-3 |
3 | Ojukwu | 2018 | Odili | 1-2 |
4 | Poison Ivy | |||
5 | The Suncity | Chris | 1 | |
6 | Singles Ladies | |||
7 | Before 30 | |||
8 | Skinny Girl in Transit |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Okwara, Vanessa (2018-12-09). "Kenneth Okolie: Good-looking dude". Newtelegraph (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-16. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ "Kenneth Okolie - iBAKATV | Home for Nollywood Movies". ibakatv.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-16. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ "Former Mr. Nigeria And Actor Kenneth Okolie; All You Need To Know About Him". 246hits.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-20. Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Former Mr Nigeria, Kenneth Okoli breaks hearts as he shows off his girlfriend for the first time". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-02-09. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Finalists square up for Mr Nigeria 2018". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Published. "Marriage cannot change my hot body – Former Mr. Nigeria, Kenneth Okolie". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Famakin, Opeyemi (2018-02-23). "7 Things You Didn’t Know About Former Mr. Nigeria And Actor Kenneth Okolie". vibe.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Olayinka (2018-02-23). "Everything You Need To Know About Former Mr. Nigeria And Actor Kenneth Okolie". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Famakin, Opeyemi (2018-02-23). "7 Things You Didn’t Know About Former Mr. Nigeria And Actor Kenneth Okolie". vibe.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Kenneth Okolie – Silverbird Mr Nigeria". www.mrnigeriasilverbird.com. Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Adeniran, Raphel (2019-03-23). "Nollywood Celebrities Who Rose To Fame From Reality Shows". Eelive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-16.
- ↑ Published. "It’s not true I shun low-budget movies – Kenneth Okolie". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "I still have a crush on Ufuoma Ejenobor – Kenneth Okolie". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-03-14. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Ugonna, Chinenye (2014-10-26). "Dating actresses bad for business– Kenneth Okolie - Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-16.
- ↑ Ochuwa, Akashat (2017-10-09). "List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". Concise News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-16. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ Aghahowa, Isoken (2019-10-31). "Nollywood Alive Actor Of The Week - Kenneth Okolie". Nollywood Alive (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-11-08. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Omotayo, Joseph (2019-09-15). "Joy as Nollywood actor Kenneth Okolie and wife, Jessica welcome their 1st child". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Bodunrin, Sola (2017-04-16). "Ladies! THIS former Mr Nigeria is off the market (photos)". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ allure1 (2017-01-11). "Former Mr Nigeria, Kenneth Okolie gets engaged for the second time (Photos)". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ Inyang, Ifreke (2012-12-18). "Revealed: Former Mr. Nigeria, Kenneth Okolie was kidnapped with Nkiru Sylvanus". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ says, Lilian (2012-12-21). "Kidnappers release Nkiru Sylvanus and Kenneth Okolie". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Nkiru Sylvanus and Kenneth Okolie Released By Kidnappers ⋆". www.herald.ng. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Kenneth Okolie and Nkiru Sylvanus Regain Freedom". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "News Flash: Nkiru Sylvanus, Kenneth Okolie Regain Freedom". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Nkiru Sylvanus, Kenneth Okolie released!". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-12-21. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "'Gbomo Gbomo Express' Movie featuring Ramsey Nouah, Gideon Okeke, Osas Ighodaro gets release date". www.pulse.ng. Archived from the original on 2019-12-16. Retrieved 2019-12-16.
- ↑ ""The Royal Hibiscus Hotel" Stars Zainab Balogun And Kenneth Okolie Cover Guardian Life Today". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-04. Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15.
- ↑ "Zainab Balogun, Kenneth Okolie star in ‘Royal Hibiscus Hotel’ movie » Entertainment » Tribune Online". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-08-19. Retrieved 2019-12-15.