Khabirat Kafidipe
Kabirah Kafidipe | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1996–present |
Gbajúmọ̀ fún | Dazzling Mirage The Narrow Path Iwalewa The White Handkerchief |
Kabirah Kafidipe jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí Araparegangan fún ipa tí ó kó nínú eré Saworoide ní ọdún 1999 èyí tí Tunde Kelani gbé jáde.[1][2]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Kafidipe ní ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje. Ó jẹ́ ọmọ ìlú Ikereku ní Abẹ́òkúta. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Abeokuta Grammar School kí ó tó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Olabisi Onabanjo University níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò Mass Communication.[3]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kabirah bẹ̀rẹ́ eré ṣíṣe pèlú eré The White Handkerchief. Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa nínú eré Saworoide ní ọdún 1999 pẹ̀lú àwọn òṣèré gbajúmọ̀ bíi Kunle Afolayan, Peter Fatomilola, Kola Oyewo, Yemi Shodimu[4]. Ní ọdún 2004, ó kópa nínú eré The Campus Queen. [5]Ipa tí ó kó nínú eré Iwalewa ni ó jẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Award.[6][7] Ní ọdún 2014, ó kópa nínú eré dírámà Dazzling Mirage.[8][9] Ó gbé eré ti rẹ̀ jáde ní ọdún 2015, ó sì pe àkòrí rẹ ní Bintu.[10]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Latestnigeriannews. "Why Khabirat Kafidipe is scared of Nigerian men". Latest Nigerian News.
- ↑ "Ayo Mogaji, Kafidipe for Awoyes Premiere". Modern Ghana.
- ↑ "Nigerian men scare me –Khabirat Kafidipe". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "MEN IN NIGERIA ARE OPPORTUNISTS----KABIRAT KAFIDIPE". nigeriafilms.com. Archived from the original on 2015-04-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ agboola. "When pages flip to inhabit screens". Weekly Trust.
- ↑ Coker, Onikepo (4 May 2007). "Africa Celebrates Film Industry at AMAA 2007". Mshale Newspaper (Minneapolis, USA: Mshale Communications). Archived from the original on 3 March 2012. https://web.archive.org/web/20120303204433/http://www.mshale.com/article.cfm?articleID=1407. Retrieved 5 April 2015.
- ↑ "AMAA Awards and Nominees 2007". African Movie Academy Award. Archived from the original on 12 October 2010. Retrieved 5 April 2015.
- ↑ Victor Akande. "Tunde Kelani’s Dazzling Mirage premieres today". The Nation.
- ↑ Daily Times Nigeria. "Daily Times Nigeria". Archived from the original on 8 November 2014. Retrieved 5 November 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "We will celebrate Bintu home and abroad –Kabirah". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-08. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)