Jump to content

Kikelomo Longe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kíkẹ́lọmọ Longẹ ni Kọmíṣánna fún Oko-owo àti Ile Iṣẹ́ ni akoko yii ní Ipinle Ogun . [1]

Ìbẹ̀rẹ̀ Igbesi ayé àti ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kíkẹ́lọmọ Longẹ jẹ́ ọmọ bíbí ìjọba ibilẹ Gusu Abeokuta. Ó kẹkọ nipa Isiro Owo ni ile ẹkọ giga Yunifasiti Ìlú Eko. Ó si di Komiṣana fun Oko-owo ati Ile Iṣẹ ni ipinlẹ Ogun nigbati Gomina Dapo Abiodun pe e wale lati Ilu Ọba (United Kingdom)[2]

Kíkẹ́lọmọ Longẹ ti fi ìgbà kan jẹ́ olórí ẹ̀ka ti o n bojuto idokowo ati àkóso inawo ni ile iṣẹ African Capital Alliance (ACA)[3]. O darapọ mó ile iṣẹ naa ni ọdun 1999 o si ni igbega titi o fi di igbakeji Aare. Oun ni o ni ojuṣe fun ohun gbogbo ti o jẹ mo itaja, ikowojo ati idokowo ni ile iṣẹ naa

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. https://www.thisdaylive.com/index.php/2020/01/07/ogun-assembly-confirms-commissioner-nominee-longe/
  2. https://businessday.ng/interview/article/we-have-begun-aggressive-drive-to-attract-more-investments-to-ogun-longe/
  3. https://www.avca-africa.org/people/kikelomo-longe/