Klorídì alumíníọ́mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Klorídì alumíníọ́mù
{{{Alt}}}
{{{Alt}}}
Àwọn orúkọ mìíràn klorídì alumíníọ́mù(III)
Identifiers
CAS number 7446-70-0 (anhydrous),
10124-27-3 (hydrate),
7784-13-6 (hexahydrate)
PubChem 24012
ChEBI CHEBI:30114
nọ́mbà RTECS BD0530000
ATC code D10AX01
SMILES
InChI
InChI key VSCWAEJMTAWNJL-DFZHHIFOAR
ChemSpider ID 22445
Properties
Molecular formula AlCl3
Molar mass 133.34 g/mol (anhydrous)
241.43 g/mol (hexahydrate)
Appearance white or pale yellow solid,
hygroscopic
Density 2.48 g/cm3 (anhydrous)
1.3 g/cm3 (hexahydrate)
Ojúàmì ìyọ́

192.4 °C *(anhydrous)
100 °C (hexahydrate)

Ojúàmì ìhó

120 °C (hexahydrate)

Solubility in water 43.9 g/100 ml (0 °C)
44.9 g/100 ml (10 °C)
45.8 g/100 ml (20 °C)
46.6 g/100 ml (30 °C)
47.3 g/100 ml (40 °C)
48.1 g/100 ml (60 °C)
48.6 g/100 ml (80 °C)
49 g/100 ml (100 °C)
Solubility soluble in hydrogen chloride, ethanol, chloroform, carbon tetrachloride
slightly soluble in benzene
Structure
Crystal structure Monoclinic, mS16
Space group C12/m1, No. 12
Jẹ́ómẹ́trì
ìjọfẹnukò
Octahedral (solid)
Tetrahedral (liquid)
Molecular shape Trigonal planar
(monomeric vapour)
Thermochemistry
Std enthalpy of
formation
ΔfHo298
−704 kJ·mol−1[1]
Standard molar
entropy
So298
111 J·mol−1·K−1[1]
Hazards
EU classification Corrosive (C)
R-phrases R34
S-phrases (S1/2), S7/8, S28, S45
LD50 anhydrous:
380 mg/kg, rat (oral)
hexahydrate:
3311 mg/kg, rat (oral)
Related compounds
Other anions Aluminium fluoride
Aluminium bromide
Aluminium iodide
Other cations Boron trichloride
Gallium trichloride
Indium(III) chloride
Magnesium chloride
Related Lewis acids Iron(III) chloride
Boron trifluoride
 Yes check.svgY (what is this?)  (verify)
Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa)
Infobox references

Klorídì alumíníọ́mù (AlCl3) ni àdàpọ̀ pàtàkì ti alumíníọ́mù àti klorínì. Funfun ni àwọ̀ rẹ̀, sùgbọ́n ó sábà ní ìdọ̀tí triklorídì irin tó únsọ àwọ̀ rẹ̀ di pípọ́n. Tó bá jẹ́ adirapọ̀, ó ní ojúàmì ìyọ́ ati ìhó kúkúrú. Níbi tí wọ́n ti únṣe ẹ̀ṣọ́ alumíníọ́mù ni wọ́n ti únsábà ṣe é àti lò ó, sùgbọ́n ó tún wúlò ní àwọn ilẹ́-iṣẹ́ kẹ́míkà míràn. Wọ́n sábà tọ́ka sí àdàpọ̀ yìí bíi ásìdì Lewis. Ó jẹ́ àpẹrẹ àdàpọ̀ àìníọ́rgánì tó "únfọ́" ní tẹ́mprétọ̀ tó lọ́wọ́rọ́, láti yípadà sẹ́yìn láti polymermólékùlù.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Zumdahl, Steven S. (2009). Chemical Principles 6th Ed.. Houghton Mifflin Company. ISBN 0-618-94690-X.