Ẹ̀ka:Àwọn klorídì
Ìrísí
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Àwọn klorídì |
Ẹ̀ka yìí wà fún àwọn àdàpọ̀ kẹ́míkà àìníọ́rgánì tí wọ́n ní klorínì. Àwọn yìí le jẹ́ iyọ̀ mẹ́tàlì tó ní íónì klorídì bíi klorídì sódíọ̀mù, tàbí àwọn klorídì àjọdìmú ti mẹ́tàlì tàbí àìjẹ́mẹ́tàlì bíi klorídì titáníọ̀mù(IV) tàbí kárbọ̀n tẹtraklorídì.