Kofi Adjorlolo
Kofi Adjorlolo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 14 June 1956 Keta– Volta region Ghana |
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Keta Senior High Technical School |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 1980–present |
Awards | International Golden Image award |
Kofi Adjorlolo (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹta ọdún 1956 ní ìlú Keta) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana.
Wọ́n ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ̀ òṣèrékùnrin tó dára jù rí ní Ghana Movie Awards, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ti yàn án nígbà mẹ́rin tí fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrẹ́kùnrin tó dára jù ní, Ghana Movie Awards, Africa Movie Academy Awards, àti ní Africa Magic Viewers Choice Awards. Lára àwọn àmì-ẹ̀yẹ mìíràn tó ti gbà ni International Golden Image award láti ọwọ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Liberia nígbà kan rí, ìyẹn Ààrẹ Ellen Johnson Sirleaf,[1] àti àmì-ẹ̀yẹ Best Cameo Actor ní 2011 Ghana Movie Awards.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Kofi Adjorlolo sí ìlú Keta, ní agbègbè Volta, ní Ghana. Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni ó ti nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́-ọnà, pàápàá jù lọ orin, àmọ́ iṣẹ́ eré ṣíṣe ló padà ṣe nígbà tí ó dàgbà. Adjorlolo tẹ̀síwájú nínú ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Ghana, ó lọ sí Keta Senior High Technical School, níbi tí àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní farahàn, látàri àwọn ìkópa rẹ̀ nínú àwọn ayẹyẹ ilé-ìwé náà. [2][3]
Àṣàyàn àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
2003 | The Chosen One Part 1&2 | Deacon Prempeh | |
2006 | My Mother's Heart | Boakye | Nominated for Best Actor (Supporting Role) at the 2nd Africa Movie Academy Awards |
2007 | Princess Tyra | King | |
2009 | Heart of Men | Bernard | |
2009 | Agony of Christ | ||
2010 | The Beast | Dr. Brooks | Nominated for Best Actor in a Supporting Role (English) at the 2010 Ghana Movie Awards |
2011 | Ties that Bind | Father | |
2011 | Somewhere in Africa | General Olemba | Winner, Best Cameo Actor at the 2011 Ghana Movie Awards |
2012 | Adesuwa (A Wasted Lust) | ||
2012 | Single and Married | Ranesh | |
2012 | Wipe My Tears | Nominated for Best Actor in a Lead Role (English) at the 2012 Ghana Movie Awards | |
2014 | Family Album | Nominated for Best Actor in a Supporting Role at the 2014 Ghana Movie Awards | |
2014 | A Northern Affair | ||
2015 | Code of Silence | ||
2015 | Falling | Mr Mazi Mba | |
2016 | Ghana Must Go | father | Nominated for Best Supporting Actor Movie/TV series at the 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards |
2017 | Crime Suspect | ||
2018 | That Night | ||
2019 | Hero: Inspired by the Extraordinary Life and Times of Mr. Ulric Cross[4] | Asantehene | |
2020 | Aloe Vera[5][6] | Papa Aloe |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Kofi Adjorlolo, Osu Mantse honoured in Liberia". Ghana Web. 24 July 2017. Archived from the original on 24 April 2019. https://web.archive.org/web/20190424083626/https://www.ghanaweb.com/GhanaHomePage/NewsArchive/Kofi-Adjorlolo-Osu-Mantse-honoured-in-Liberia-562055. Retrieved 24 November 2018.
- ↑ "Kofi Adjorlolo's Early Life and Career Journey". GhanaWeb. 2019.
- ↑ "A Look at Kofi Adjorlolo’s Formative Years". MyJoyOnline.com. 2020.
- ↑ Solomon, Frances-Anne (22 June 2019), HERO Inspired by the Extraordinary Life & Times of Mr. Ulric Cross (Drama), Kofi Adjorlolo, Jimmy Akingbola, Giles Alderson, Tessa Alexander, HeroFilm, HeroFilm, CaribbeanTales, retrieved 2021-02-03
- ↑ Sedufia, Peter (6 March 2020), Aloevera (Drama, Romance), Benjamin Adaletey, Aaron Adatsi, Ngozi Viola Adikwu, Kofi Adjorlolo, OldFilm Productions, retrieved 2021-02-03
- ↑ "Film review: Aloe Vera offers some charm in its vibrant retort to irrational tribalism". Citinewsroom – Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 March 2020. Retrieved 2021-02-03.