Agony of Christ (film)
Ìrísí
Agony Of Christ | |
---|---|
Adarí | Frank Rajah Arase |
Olùgbékalẹ̀ | Abdul Salam Mumuni |
Òǹkọ̀wé | Abdul Salam Mumuni |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Venus Films Production |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Ghana |
Èdè | English |
Agony of Christ jẹ́ fíìmù Ghana tó jáde ní ọdún 2009, tí Frank Rajah Arase darí.[1]
Àhunpọ̀ ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Arákùnrin kan sá kúrò ní ìlú rẹ̀ nítorí ìyá-aláwo ìlú náà fẹ́ pa á. Àwọn ẹlésìn Kìrìsìtẹ́ẹ̀nì kan ló kó o yọ, tí wọ́n sì tọ sọ́nà láti mọ ẹ̀sìn náà, tí ó fi di àtúnbí. Ó padà sí ìlú rẹ̀, níbi tí wọ́n ti ń sin àwọn òòṣà kékèèké. Ó gbìyànjù láti yí ọkàn àwọn ará-ìlú náà pada, àmọ́ ìyá-aláwo ìlú náà ò fi àyè gbà á, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní gbógun ti arákùnrin yìí.[2]
Àwọn òṣèré tó kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Majid Michel
- Nadia Buari
- Kofi Adjorlolo
- Eddie Nartey
- Naana Hayford
- Solomon Sampah
- Yvonne Okoro
- Kofi Adjorlolo
- Samuel Nii Odoi Mensah
- Prince David Osei
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ nollywoodreinvented (2012-11-02). "Agony of the Christ". Nollywood Reinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-29.
- ↑ Francis Addo, Francis. "Agony Of The Christ' Premiered". Modern Ghana. Francis Addo. Retrieved 8 November 2018.