Yvonne Okoro
Yvonne Okoro | |
---|---|
Yvonne Okoro at the 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards | |
Ọjọ́ìbí | Chinyere Yvonne Okoro 25 Oṣù Kọkànlá 1984 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria, Ghana |
Iṣẹ́ | Osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002–present |
Website | yvonneokoro.com/ |
Chinyere Yvonne Okoro je osere omo Nàìjíríà ati Ghánà. Baba e wa lati Naijiria, iya e si wa lati Ghana. Okoro je omo oniran pupo, nitori eyi ni ofin man pe ara re ni omo Áfríkà. Yvonne Okoro wa lati Amankalu Alayi ni Ìpínlẹ̀ Ábíá, ilu Naijiria.
O gba ami eye osere ti o dara ju lo ni odun 2010 ni Ghana Movies Award.[1] won si yan fun osere ti odara julo fun Africa movie academy awards lesese ni odun 2011 ati 2012 fun awon fiimu Pool Party ati Single Six[2] O ti gba ami eye merin lati odo Africa magic viewers' choice award[3] ni odun 2012 won fun ni ami eye fun ipa ti oyato ni Nigeria Excellence Awards[4][5]
Igbesi aye ibẹrẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nitori iya e je omo Ghana ti baba e sin je omo Naijiria, oje omo iran adapo, nitori idi eyi ni ofi man pe ara e ni omo Africa[6] Owa lati ebi ti o tobi, ohun ni akobi iya e, osi je elekarun fun baba e. Lati igba ti oti wa ni omode ni oti feran ki oma se ere. Olosi Achimota Preparatory School, lehin nah o lo si Lincoln Community School lehin na olosi Faith Montessori School. O losi Mfantsiman Girls Secondary School lehin igna na ni owa lo si University of Ghana, Legon ni ibi ti oti gba oye Awonran, pelu ede ati imo-ede. Otun lo si Universite de Nantes ni Fránsì lati lo ko eko ni pa iroyin, ere ati tita oja.[7]
Iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O bere si ni se ere ni odun 2002, ere ti o ko kopa ninu e ni Sticking to the Promise, eleyi ti Theo Akatungba dari[8] tun ko ipa kekere ninu jara Tentacles, ti Theo Akatungba dari, Point Blank Media Concepts ni o gbe jade.
O n se agbalejo eto sise ounje kan, Cooks and Braggarts. Eto yi je eto ti awon gbajumo man wa lati se orisiri ounje, won osi ma soro nipa nkan orisirisi ton sele ni awujo.
Awon owo imi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O so fun ile ise Redio, Peace Fm ti o wa ni Accra pe ohun ni ile ise ti ti ohun Desamour Company Limited. Otun so wipe ohun ni ile ise oko kan na[9]
Inurere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni odun 2019, o fi owo kale fun awon arewa omoba dudu titi ile Ghana ni pase idije WAFA ni odun 2019, osi tun se itore si iyewu alaboyun titi Korle bu Teaching Hospital.[10]
Asayan ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Queen Lateefah
- Mother's love
- Beyonce: The President's Daughter
- The Return Of Beyonce
- The President's Daughter
- Desperate To Survive
- The Game
- Agony Of Christ
- Royal Battle
- Queen Of Dreams
- ‘Le Hotelier’ in France
- Pool Party
- Sticking to the promise
- Single Six
- Why Marry
- Best Friends (Three can play)
- Blood is Thick
- Four Play
- Four Play reloaded
- Forbidden City
- Contract (28th dec. 2012) with Hlomlo dandala.[11]
- I Broke my Heart
- Adams Apples film series (2011–2012)
- Crime
- Ghana Must Go (2016)[12]
- Rebecca (2016)[13]
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Yvonne Okoro, Efya Made Ambassadors For Head Of State Awards". dailyguideghana.com. Archived from the original on 23 September 2015. Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "10 things you don't know about Yvonne". Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "Yvonne Okoro, Efya Made Ambassadors For Head Of State Awards". dailyguideghana.com. Archived from the original on 23 September 2015. Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "BUZZ Yvonne Okoro honoured by Nigeria Excellence Awards". Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "Yvonne Okoro". ghananation.com. Archived from the original on 22 February 2015. Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "10 things you don't know about Yvonne". Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "10 things you don't know about Yvonne". Retrieved 22 February 2015.
- ↑ "10 things you don't know about Yvonne". Retrieved 22 February 2015.
- ↑ Lamptey, Edwin (2018-06-10). "Yvonne Okoro is super rich. Here are some companies she owns as an entrepreneur". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-24.
- ↑ "Yvonne Okoro pays bills of 13 new mothers at Korle Bu Teaching Hospital – Glitz Africa Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-24.
- ↑ "Link text, additional text.". Archived from the original on 2013-06-28. Retrieved 2020-10-17.
- ↑ "Everything you need to know about Yvonne Okoro's upcoming movie". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 16 August 2016. Retrieved 19 May 2015.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-20. Retrieved 2020-10-17.