Jump to content

Kuku Paka

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kuku Paka jẹ́ ọbẹ̀ adìẹ pẹ̀lú ohun èlò coconut-based curry[1] wọ́n sì tún máa ń pè é ní “kuku na nazi”. Ó ní agbára ilẹ̀ African, Indian àti Arabic. Kuku ní Swahili túmọ̀ sí adìẹ.[2][3] Oúnjẹ náà gbajúmọ̀ pàápàá jù lọ ní ẹkùn East African àti láàárín àwọn àwùjọ Indian tí wọ́n ń gbé ní Kenya, Tanzania àti Uganda. Paka ní Swahili tẹ́, tàn ká tàbí lò.

Coconut milk tàbí coconut cream àti ohun èlò kọrí ni àwọn èròjà tó ṣe pàtàkì jù lọ fún oúnjẹ náà. Ohun tí ó ya Kuku Paka sọ́tọ̀ sí àwọn kọrí àgbọn tó kù ni adùn láti ara lílọ ẹran adìẹ náà síwájú fífi kún kọrí àgbọn. Èyí máa ń fún un ní adùn gidi. Edé tàbí ní wọn sábàá máa ń lò láti pààrọ̀ ẹran adìẹ nínú oúnjẹ ìlà-oòrùn ilẹ̀ Áfíríkà tó gbajúgbajà.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Kuku Paka (Kenyan Chicken Curry)". Food.com. Retrieved 5 August 2015. 
  2. "Kuku Paka". Congo Cookbook. Archived from the original on 2 April 2019. Retrieved 5 August 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Rubbery Chicken". Retrieved 8 March 2020. 
  4. "African Menu". Sea View Resort Malindi (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-05-16. Retrieved 2020-05-24.