Lagelu
Ìrísí
Lágelú ni ìtàn sọ pe o da ìlú Ìbàdàn sílẹ̀. Ìtàn fi ye wa wípé ibi ti o di ìlú Ìbàdàn l'óde òní bẹ̀rẹ ni ọdun 1829. Ni àkókó yi, irúkèrúdò pọ ni gbogbo ilẹ̀ Yorùbá káàkiri, eyi ni o si fa ti jagunjagun ti a n pe ni Lágelú fi wa tẹdo si ìlú Ìbàdàn. Erongba Lágelú ni lati fi ṣe ibùdó fún awon jagunjagun.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-08-02. Retrieved 2018-08-01.