Lamberto Dini

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lamberto Dini

Lamberto Dini jẹ́ Alákòso Àgbà ilẹ̀ Italia tẹ́lẹ̀. A bi ni ọjọ́ kìnní oṣù kẹta ọdún 1931. Òun ni Mínísítà Àgbà kọkàn-lé-laadọta fún orílẹ̀-èdè Italia laarin ọdụn 1995 sí 1996 àti Mínísítà fún ilẹ̀ òkèèrè láti ọdún 1996 si 2001.

Ìbèrè ìgbésí ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lẹ́yìn ti o k'ẹko ninu ìmò ètò ìṣúná owò

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]