Lateef Olufemi Okunnu
Lateef Olufemi Okunnu | |
---|---|
Pro-chancellor of the University of Agriculture, Makurdi | |
In office 1982–1984 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejì 1933 Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
Lateef Olufemi Okunnu Àdàkọ:Post-nominals tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 jẹ́ agbẹjọ́rò àgbà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Alága àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn University of Agriculture, Makurdi.[1][2]
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Lateef Okunu ní ọjọ́ kọkàndínlógún òṣù kejì ọdún 1933 ní ìlú Èkó. Ó lọ sílé ẹ̀kó alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ansarudeen, tí ó wà ní Alakoro láàrín ọdún 1938 sí 1947. Tí ó sì tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Kings College láàrín ọdún 1938 sí 1953. [3][4] Ní ọdún 1956, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ University of London níbi tí ó ti kẹ́kọ́ gbiyè akọ́kọ́ nínú ìmọ̀ òfin tí wọ́n sì gbàá wọlé gẹ́gẹ́ bí amòfin agbẹjọ́rò ní ọdún 1960, wọ́n sì tún fi jẹ Alákòóso ìjọba apápọ̀ fún iṣẹ́ àti ilégbèé. [5][6]Ó ṣakóso gẹ́gẹ́ bí adarí ní ipò yí fún ọdún méje tí sáà rẹ̀ sì tẹnubepo ní ọdún 1974. Wọ́n t tún yàn án gẹ́gẹ́ bí olùgbani nímọ̀ọ̀ràn amòfin fún ẹgbẹ́ He served in this capacity for seven years, a tenure that ended in 1974 National Party of Nigeria (N.P.N.) ní ọdún 1981.[7]
Iṣẹ́ tí ìjọba yàn án
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìjọba yàn án gẹ́gẹ́bí agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú àpérò Organisation of African Unity Consultative Committee nípa sísọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àlááfíà látàrí ogun abẹ́lé tí ó wáyé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà láàrín ọdún 1968 àti ti ọdún 1969, Ìjọba tún yàn án gẹ́gẹ́bí agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú àpérò O.A.U. Ministerial Conference. Ní ọdún 1980, òun ni ó ṣe agbẹnusọ fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní inú àpérò U.N.O. Lẹ́yìn náà ni wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Alákòóso àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ fáfitì University of Agriculture, Makurdi ní ọdún 1982.
Awọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Senior Advocate of Nigeria (S.A.N)
- Commander of the Order of the Republic of Niger (CON)
- Commander de I, Ordre National Du Dahomey and Commander National Order of Togo.
- He was awarded with an honorary doctorate degree during the 50th convocation ceremony of the University of Lagos [1][Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Òun ni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]"Olúfẹ́mi" tí ó túmọ̀ sí Oluwaẹ́mi [8]
Àwọn itọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "I was taught to respect opposing views - Lateef Okunnu - Vanguard News". Vanguard News. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ "Aregbesola backs Jihad, flays Boko Haram attacks". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 5 December 2014. Retrieved 28 November 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigeria's first Ansar-ud-den College of Education clocks 10, says school not for Musilms [sic] alone". DailyPost Nigeria. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ RapidxHTML. "The Nigeria Academy of Engineering :: promoting excellence in technology and engineering training and practice to ensure the technological growth and economic development of Nigeria". Archived from the original on 6 December 2014. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ Amidu Arije. "‘Boko Haram doesn’t represent Islam’". Retrieved 28 November 2014.
- ↑ "[General] The Femi Okunnu Interview [Part 1: Dangers of Zoning]". Village Square Forum. Archived from the original on 4 December 2014. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ "Olufemi Okunnu kills federation - The Nigerian Eye Newspaper: Breaking news in Nigeria as well as Nigerian News, ghana news, information and opinion on sports, business, politics and more from Nigeria's most read newspaper.". Archived from the original on 4 December 2014. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ "Olufemi". Behind the Name. Retrieved December 20, 2014.
- Pages with citations using unsupported parameters
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from January 2024
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- 20th-century Nigerian lawyers
- 1933 births
- Living people
- Lagos State lawyers
- Alumni of the University of London
- King's College, Lagos alumni
- Yoruba legal professionals
- Academic staff of the University of Agriculture, Makurdi