Jump to content

Lopo do Nascimento

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Lopo do Nascimento Ojo ibi re ni ojo kewa osu agemo ni odun 1942, O je okan lara awon oloselu angola to ti fehinti, O je Alakoso Agba ile Angola tele lati ojo kokanla osu beelu ni odun 1975 titi di ojo kesan osu ope ni odun 1978.O tun je akowe agba patapata fun lilo bibo fun ominirailu angola [MPLA].Nigbati o pe omo odun metadinlogun won mu sugbon won tun fi sile pelu pipa ni dandan fun ko koja si ilu Cuanza Norte

Lopo do Nascimento