Louis 16k ilẹ̀ Fránsì
Jump to navigation
Jump to search
Louis XVI | |
---|---|
![]() | |
Louis XVI by Antoine-François Callet | |
Reign | 10 May 1774 – 1 October 1791 ( ọdún 17 , ọjọ́ 144 ) |
Coronation | 11 June 1775 | (ọmọ ọdún 20)
Predecessor | Louis XV |
Successor | Himself as King of the French |
Reign | 1 October 1791 – 21 September 1792 |
Predecessor | Himself as King of France and Navarre |
Successor | Monarchy abolished National Convention ruling legislative body of the French First Republic Louis XVII as the de jure successor and heir. Next reigning monarch in France was Napoleon I starting 1804. |
Spouse | Marie Antoinette |
Issue | |
Marie Thérèse, Queen of France and Navarre Louis Joseph, Dauphin of France Louis XVII of France Princess Sophie | |
Full name | |
Louis Auguste de France | |
House | House of Bourbon |
Father | Louis, Dauphin of France |
Mother | Marie-Josèphe of Saxony |
Burial | 21 January 1815 Saint Denis Basilica, France |
Signature | ![]() |
Religion | Roman Catholicism |
Louis Kẹrìndínlógún (23 August 1754 – 21 January 1793) je bi Oba ile Fransi ati Naffarre lati 1774 titi di 1791, ati leyin igba na bi Oba awon ara Fransi lati 1791 de 1792. O je didalowo ati fifofinmu gege bi apa jagidijagan ojo 10k osu kejo 1792 nigba Ijidide Fransi, o je didalejo latowo Ipejo Olomoorile-ede, o si je didalebi esun idale, o si je sisekupa pelu guillotini ni 21 January 1793. Ohun nikan ni oba ile Fransi to je sisekupa.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |