Napoleon Bonaparte

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Napoleon Àkọ́kọ́
Full length portrait of a man in his forties, in high-ranking dress white and dark blue military uniform. He stands amid rich 18th-century furniture laden with papers, and gazes at the viewer. His hair is Brutus style, cropped close but with a short fringe in front, and his right hand is tucked in his waistcoat.
The Emperor Napoleon in His Study at the Tuileries, by Jacques-Louis David, 1812
Emperor of the French
Reign 18 May 1804 – 11 April 1814
20 March 1815 – 22 June 1815
Coronation 2 December 1804
Predecessor French Consulate
Himself as First Consul of the French First Republic.

Previous ruling monarch was Louis XVI as King of the French (1791-1792)

Successor Louis XVIII (de jure in 1814; as legitimate monarch in 1815)
Napoleon II (according to his father's will of 1815)
King of Italy
Reign 17 March 1805 – 11 April 1814
Coronation 26 May 1805
Predecessor Himself as President of the Italian Republic.

Previous ruling monarch was Emperor Charles V, crowned in Bologna in 1530

Successor Kingdom disbanded
Next monarch crowned in Milan was Emperor Ferdinand I, next king of Italy was Victor Emmanuel II of Savoy
Spouse Joséphine de Beauharnais
Marie Louise of Austria
Issue
Napoleon II of France
Full name
Napoleon Bonaparte
House House of Bonaparte
Father Carlo Buonaparte
Mother Letizia Ramolino
Burial Les Invalides, Paris

Napoleon Bonaparte (15 August 1769 – 5 May 1821) ti a mo ni gbeyin bi Napoleon Akoko ti o si je Napoleon di Buoaparte je olori ologun ati oloselu ile Faranse ti ise re fara kan iselu Europe ni orundun 19k.

Wón bí Napoleon Bonaparte ní odún 1769 ó sì kú ní odún 1821. Odún 1789 ni French Revolution lé Louis XVI kúrò ní orí oyè tí ilè Faransé sì di republic. Kò pé tí Napoleon di emperor ilè Faranse. Ele era um Mahagadha. Ajaccio tí ó wà ní erékùsù Corsica ni wón ti bí Nepoleon. Abé ilè Faranse ni Corsica wa. Ó kó isé ológun ó sì ségun òpòlopò òtè tí ó n selè ní ilè Faranse ní ìgbà náà kí ó tó wá so ara rè di emperor ní 1804 níwájú Pope Pius VII ní Paris. Ó ségun púpò nínú ilè ìlú Òyìnbó. Ó féé so ara rè di emperor gbogbo ìlú Òyìnbó sùgbón àwon ilè wònyí kò gbà fún un. Wón ségun rè ní Waterloo ní 1815. Àwon olórí ogun méjì tí ó se pàtàkì àti Blucher ti Prussia. Wón lo fi Napoleon sí àhámó ní St Helena. Ibè ni ó kú sí ní 1821.

Ènìyàn kúkurú ni Napoleon nítorí ìdí èyí wón máa n pè é ní ìnagije ‘little corporal’. Àwón sójà rè máa n bòwò fún un. Ìyàwó rè àkókó tí orúko rè n jé Josephine de Beauharnais ràn án lówó láti dé orí oyè.


Itoka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]