Lucrécia Paco
Lucrécia Paco | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹ̀wá 1969 Maputo, Mozambique |
Orílẹ̀-èdè | Mozambican |
Iṣẹ́ | osere |
Ìgbà iṣẹ́ | 1984-titi di isinyi |
Lucrécia Paco (ti a bi ni ojo kankandilogun osu kewa odun 1969) je osere ti o wa lati ilu Mozambique. O je okan larin awon osere ti oniyi ju ni Mozambique.
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Paco dagba ni Maputo. Ni igba ti owa ni omode, o feran ki oma ko orin ati ki o ma jo si awon orin ibile, eleyi ti ko po nita ki Mozambique to gba ominira ni odun 1975. Ko da wan Paco ni ile iwe nitori o man so ede ibile. Lehin ominira awon egbe sosialisiti gba won ni iyanju ki won ma se ere itage ati bebelo, Paco si kopa ninu ijo, orin ati ewi kika.[1]
Ni asiko Ogun abele Mozambique, Paco fi akiyesi eh si ara ere itage gege bi ise oselu. O ko ipa ninu ere itan titi 1984 Maputo Mulher.[2] Ni odun 1986 Paco wa lara awon oludasile Mutumbela Gogo troupe, egbe ere itage akoko ni Mozambique, ti osi wa di eni. Awon ere Soviet ti owo lo wu lori lofi se awon ere kukuru nipa bi o se ri ki eyan ma gbe ni Mozambique. Ki won ba le se olugbowo egbe ere itage na, won ko ile ise buredi.[3]
Paco fun ra e ni isnmi odun marun nitori pe o re[4] Ni odun 2009 Instituto Itaú Cultural pe Paco wa si ilu Brasil. O ko ipa ninu project antidote pelu ere Mulher Asfalto.[5] Ni odun 2009 mu Paco gege bi olukopa ninu ere Quero Ser uma Estrela. Lehin igba na oko ipa kan ninu Nineteens ere Telenovela akoko titi Mozambique.
Awon ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Telefisonu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Odun | Akori | Ipa |
---|---|---|
2010 | Nineteens | Glória Monjane |
2002 | A Jóia de África | Abibi |
Fiimu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role |
---|---|---|
2010 | Quero Ser uma Estrela | Obinrin[6] |
2010 | Flores Silvestres | [7] |
1998 | Nelio's Story | Maria[8] |
1986 | O Vento Sopra do Norte | |
1984 | Maputo Mulher |
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Lucrecia Paco". Club of Mozambique. 5 July 2016. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Pila, Elton. "Lucrécia paco:Uma vida em que cabem muitas vidas". Literatas. Archived from the original on 16 October 2020. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ Gomes, Christiane (September 2011). "LUCRÉCIA PACO E O TEATRO COMO FERRAMENTA DE TRANSFORMAÇÃO SOCIAL" (in Portuguese). Omenelick. Archived from the original on 26 November 2013. Retrieved 8 October 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ http://omelete.uol.com.br/filmes/quero-ser-uma-estrela/elenco/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-02-01. Retrieved 2020-10-17.
- ↑ http://www.cineplex.com/Movie/comedia-infantil