Luisa Diogo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Luisa Diogo
Diogo at the World Economic Forum Annual Meeting 2009.
Alakoso Agba ile Mozambique
In office
17 February 2004 – 16 January 2010
ÀàrẹJoaquim Chissano
Armando Guebuza
AsíwájúPascoal Mocumbi
Arọ́pòAires Ali
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kẹrin 1958 (1958-04-11) (ọmọ ọdún 66)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLiberation Front
Alma materEduardo Mondlane University
School of Oriental and African Studies

Luísa Dias Diogo (ojoibi April 11, 1958) je Alakoso Agba orile-ede Mozambique lati February 2004 titi di January 2010. O dipo Pascoal Mocumbi, to ti je Alakoso Agba fun odun mesan. Ki o to di Alakoso Agba, o je Alakoso Iseto ati Isuna, ipo to dimu titi di February 2005.[2]Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]