Ma Ying-jeou

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ma Ying-jeou
馬英九
12th-term President of the Republic of China
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
May 20, 2008
Premier Liu Chao-shiuan
Wu Den-yih
Vice President Vincent Siew
Asíwájú Chen Shui-bian
6th Chairman of the Kuomintang
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
October 17, 2009
Asíwájú Wu Po-hsiung
4th Chairman of the Kuomintang
Lórí àga
July 27, 2005 – February 13, 2007
Asíwájú Lien Chan
Arọ́pò Wu Po-hsiung
Mayor of Taipei
Lórí àga
December 25, 1998 – December 25, 2006
Asíwájú Chen Shui-bian
Arọ́pò Hau Lung-pin
Personal details
Ọjọ́ìbí 13 Oṣù Keje 1950 (1950-07-13) (ọmọ ọdún 69)
Yau Ma Tei, Kowloon, Hong Kong
Nationality Republic of China
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Kuomintang
Spouse(s) Christine Chow Ma
Alma mater National Taiwan University
New York University
Harvard University
Website www.president.gov.tw
Ma Ying-jeou
Traditional Chinese
Simplified Chinese

Ma Ying-jeou (Àdàkọ:Zh; born July 13, 1950) ni Aare ikejila lowolowo orile-ede Olominira ile Saina (ROC), to gbajumo bi Taiwan, o tun je Alaga egbe oloselu Kuomintang, ti a mo gge bi Egbe Oloselu Asorile-ede ti Saina. Teletele o je Alakoso Oro Idajo lati 1993 de 1996, Baale ilu Taipei lati 1998 de 2006, ati Alaga Kuomintang (KMT) lati 2005 de 2007. Ma je didiboyan gege bi Baale ilu Taipei ni 1998 ati leekansi ni 2002. O je didiboyan bi Alaga Kuomintang ni July 16, 2005. O kosesile ni February 13, 2007, leyin ti o je fifesunkan latowo Ibise Afesunkan Giga Taiwan pelu esun ikowoje nigba ijoba re gege bi baale ilu Taipei;[1] won mu esun yi kuro nigbeyin. Ma bori ninu idiboyan aare odun 2008. O gori aga gege bi Aare ni May 20, 2008, ati gege bi Alaga Kuomintang ni October 17, 2009.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]