Maasai

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Maasai
Maasai women and children.jpg
A gathering of Maasai women and children in 2006
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
883,000
Regions with significant populations
 Kẹ́nyà
        (estimates vary)
377,089
or 453,000
[1]
[2]
 Tanzania (northern) 430,000
Èdè

Maa (ɔl Maa)

Ẹ̀sìn

Monotheism
including Christianity

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Samburu

Maasai je eya awon eniyan ni Apailaoorun Afrika. Wón wà ní àdúgbò orílè èdè Tanzania àti Kenya, wón sì féè tó òké métàdínlógún ààbò ní iye. Èdè won ni OI Maa wón sì múlé gbe Samburu, Kikuyu, Kamba, Chaga, Meru abbl. Darandaran tààrà ni wón. won a sì máa sín ìlèkè gan-an. Ojó orí ni wón máa fi ń se ìjoba ní ilè yìí, obìnrin won kìí sìí pé ní oko sùgbón okùnrin gbódò ní owó lówó kí ó tó fé aya. Ní àsìkò ayeye pàtàkì, màálù ni wón máa ń fi rúbo.


  1. Àṣìṣe
  2. Àṣìṣe