Madam Koi Koi
Ìrísí
Madam Koi Koi (tí a tún mọ̀ sí Lady Koi Koi, Miss Koi Koi, Madam High Heel tàbí Madam Moke ní Ghana àti Miss Konkoko ni Tanzania ) jẹ́ òkú nínú àwọn ìtàn ìgbàanì ti ilẹ̀ Nàìjíríà àti Áfíríkà tó máa ń ṣẹ̀rùbà wọ́n ní ilé-ìgbé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti Ilé-ìgbọ̀nsẹ̀ ní àwọn ilé-ìwé lálẹ́. Africa.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The legend of the dead teacher who haunts secondary school students". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-10-17. Retrieved 2021-09-29.
- ↑ "Lady Koi-Koi & Other Crazy Secondary School Stories – StyleVitae" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-22. Retrieved 2021-09-29.