Malaika Uwamahoro

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Malaika Uwamahoro
Ọjọ́ìbíMalaika Uwamahoro
1990
Rwanda
Iṣẹ́
Gbajúmọ̀ fún

Malaika Uwamahoro (bíi ni ọdún 1990) jẹ́ òṣèré, akéwì, olórin àti ajìjàgbara lórílẹ̀ èdè Rwanda.[1][2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Malaika sí Rwanda ní ọdún 1990. Nítorí ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó wáyé ní ọdún 1994, òun àti ìyá rẹ sá kúrò ní Rwanda lọ sí Uganda.[4] Ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Fordham University.[5]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kópa nínú eré Loveless Generation èyí tí Tomas Petkovski gbé kalẹ̀ ní ọdún 2018[6]. Ní ọdún náà, ó ṣe bí Princess nínú eré Yankee Hustle.[7] Ní ọdún 2019, ó farahàn nínú eré Our Lady of the Nile.[8][9][10][11][12] Ipa tí ó kó nínú eré Miracle in Rwanda ni wọ́n fi yàán fún àmì ẹ̀yẹ Best Solo Performance ní VIV Award ni ọdún 2019.[13][14] Ó wá nínú orin Stickin' 2 You èyí tí Mucyo kọ.[15] Ó wá lára àwọn tó dárà níbi ayẹyẹ DanceAfrica event ní ọdún 2019.[16] Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ìkan lára àwọn obìnrin tí wọ́n pè láti sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ Forbes Woman Africa 2020 Leading Women Summit tí wọ́n ṣe ni South Áfríkà.[17][18]

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Armstrong, Linda (April 18, 2019). "‘Miracle in Rwanda’ shows the power of faith, love, forgiveness". New York: Amsterdam News. Retrieved November 25, 2020. 
  2. Methil, Renuka (May 3, 2020). "‘Our Home Became The Film Set, Blankets Became Props, Windows Became Locations’". Forbes Africa. Retrieved November 24, 2020. 
  3. Methil, Renuka (May 3, 2020). "‘Our Home Became The Film Set, Blankets Became Props, Windows Became Locations’". Forbes Africa. Retrieved November 24, 2020. 
  4. Opobo, Moses (April 12, 2017). "Kwibuka23: Uwamahoro’s appeal to world leaders". The New Times. Retrieved November 25, 2020. 
  5. "'Learn the lessons of Rwanda,' says UN chief, calling for a future of tolerance, human rights for all". UN News. April 7, 2017. Retrieved November 25, 2020. 
  6. "LoveLess Generation (2018)". IMDb. Retrieved November 24, 2020. 
  7. "Yankee Hustle (2018– )". IMDb. Retrieved November 24, 2020. 
  8. "Our Lady of the Nile (2019)". IMDb. Retrieved November 24, 2020. 
  9. Santiago, Luiz (October 31, 2020). "CRITICISM | OUR LADY OF THE NILE". Plano Crítico. Retrieved November 25, 2020. 
  10. Keizer, Mark (September 5, 2019). "Film Review: ‘Our Lady of the Nile’". Variety. Retrieved November 25, 2020. 
  11. Lemercier, Fabien (September 6, 2019). "TORONTO 2019 Contemporary World Cinema | Review: Our Lady of the Nile". Cineuropa. Retrieved November 25, 2020. 
  12. "Drive In to the Opening Night Films from Method Fest". Broadway World. August 18, 2020. Retrieved November 25, 2020. 
  13. Hetrick, Adam (February 12, 2019). "Miracle in Rwanda Will Arrive Off-Broadway This Spring". Playbill. Retrieved November 25, 2020. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  14. Meyer, Dan (October 15, 2019). "The Secret Life of Bees, Much Ado About Nothing Lead 2019 AUDELCO’s VIV Award Nominations MEYER". Playbill. Retrieved November 25, 2020. 
  15. Kanaka, Dennis (February 19, 2020). "Kigali Creatives: The Backstory to “Stickin’ 2 You”". The New Times. Retrieved November 25, 2020. 
  16. Chavan, Manali (May 23, 2019). "Weekend Art Events: May 24-26 (DanceAfrica 2019, Coney Island History Project, Memorial Day Concert & More)". Bklykner. Retrieved November 25, 2020. 
  17. "Women Summit announces its speaker line-up". Media Unit. March 2, 2020. Retrieved November 25, 2020. 
  18. Iribagiza, Glory (February 13, 2020). "Uwamahoro to speak at Forbes 2020 women summit". The New Times. Retrieved November 24, 2020.