Malika Belbey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Malika Belbey
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹfà 15, 1974 (1974-06-15) (ọmọ ọdún 48)
Tiaret
Orílẹ̀-èdèAlgerian
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2004-present

Malika Belbey (ti abi ni ojo kedogun osu kefa odun 1974) je osere ti o wa lati ilu Àlgéríà

Igbesiaye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilu Tiaret ni won bi Belbey si, ni apa iwo oorun titi Algeria.[1]O lo si Algiers School of Dramatic arts. Belbey bere ise osere pelu ere ori itage ti akori re je ''Nedjma'' ti won mu lati iwe ti Kateb Yacine ko, ti Ziani Cherif Ayad se oludari e. O se igbajede telifisonu ni odun 2004 pelu,The Player.[2] O wo inu ajo cinema pelu Barakat![3] Ni odun 2007, o kopa ninu fiimu Morituri , eleyi ti oda lori iwe ti Yasmina Khadrako. Iwe asaragaga na da lori olopa ti o se iwadi awon egbe apanilaya ka ni asiko ogun Algerian Civil War.[4] Belbey kopa ninu jara telifisonu Djemai Family ni odun 2008. O kopa ninu Dhikra El Akhira ni odun 2010 ati 2011.[5]

Ni osu keta odun 2014 won se ike fun ni 13th Gulf Radio and TV Festival ni Bahrain.[6]Ni odun 2019 o ko ipa meji ototo ninu ere ti Sakim HAmdi se, ti osi pe akori re ni Reconnaissance. O gba ami eye osere obinrin ti odara ni Maghreb Film Festival ni Oujda, Morocco.[7] Belbey kopa ninu jara tv ti odun 2020 ti akori e je Yema.[8] O ni ipa ti ohun ko, je ipa obinrin ti oti je iya lopolopo, sugbon otun ile e ko lai bikita fun odun mewa to lo ni ewon. Lehin igba ti oka ipa yi , Belbey ofe ko iru ipa ti oko tele ri ninu jara imiran. o ba Madih Belaid se ise.[9]

.

Asayan Ere[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Fiimu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • 2006 : Barakat!
 • 2007 : Morituri
 • 2008 : Le dernier passager (fiimu kukuru)
 • 2009 : Point final 1er novembre 1954
 • 2019 : Reconnaissance

Tẹlifisiọnu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • 2004 : The Player : Sonia
 • 2006 : Le printemps noir
 • 2008 : Rendezvous with Destiny : Hanane
 • 2008 : Djemai Family : The Indian Adra (ipele akoko episode eleketadilogun)
 • 2010-2011 : Ad-Dhikra El Akhira : Halima
 • 2015 : Weld Mama
 • 2018 : Lella zineb
 • 2019 : Rays Kourso
 • 2019 : Wlad Lahlal : Zoulikha
 • 2020 : Ahwal Anes : Iya Redha
 • 2020 : Yema : Nabila

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Biographie Malika Belbey". Cineserie.com (in French). Retrieved 9 October 2020. 
 2. "Algerian actress Malika Belbey to be honoured at Gulf Radio, TV Festival in Bahrain". Arab Today. 12 March 2014. Retrieved 9 October 2020. 
 3. "«Le temps n’était plus en notre faveur»". L'Expression (in French). 14 May 2020. Retrieved 9 October 2020. 
 4. Mitchell, Wendy (22 May 2007). "Cinexport starts sales for Algerian story Morituri". Screen Daily. Retrieved 9 October 2020. 
 5. "«Le temps n’était plus en notre faveur»". L'Expression (in French). 14 May 2020. Retrieved 9 October 2020. 
 6. "Algerian actress Malika Belbey to be honoured at Gulf Radio, TV Festival in Bahrain". Arab Today. 12 March 2014. Retrieved 9 October 2020. 
 7. "«Reconnaissance» de Salim Hamdi sélectionné". Medias-dz.com (in French). 12 June 2020. Retrieved 9 October 2020. 
 8. "« Yema » le feuilleton dramatique qui dominera le ramadhan 2020 sur EL Djazairia One". DIA (in French). 17 April 2020. Retrieved 9 October 2020. 
 9. "«Le temps n’était plus en notre faveur»". L'Expression (in French). 14 May 2020. Retrieved 9 October 2020.