Mamady Doumbouya
Ìrísí
Mamady Doumbouya | |
---|---|
ߡߊ߬ߡߊߘߌ߫ ߘߎ߲ߓߎߦߊ߫ | |
Doumbouya in 2022 | |
President of Guinea | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 October 2021 | |
Alákóso Àgbà | Mohamed Béavogui Bernard Goumou Bah Oury |
Asíwájú | Alpha Condé |
Chairman of the National Committee of Reconciliation and Development | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 5 September 2021 | |
Asíwájú | Office established |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kẹta 1980 Kankan, Guinea |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Lauriane Darboux |
Àwọn ọmọ | 4 |
Military service | |
Allegiance | France (formerly) Guinea |
Branch/service | French Foreign Legion (formerly) Adigun Guinea |
Rank | Colonel |
Mamady Doumbouya (N'Ko: ߡߊ߬ߡߊߘߌ߫ ߘߎ߲ߓߎߦߊ߫, tí a bí ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 1980) jẹ́ ológun ọmọ orílẹ̀ ède Guinea, òun ni Ààrẹ orílẹ̀ ède Guinea láti ọjọ́ Kínní oṣù Kẹ̀wá ọdún 2021. Doumbouya dárí ìdìtẹ̀ gba ìjọba tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹsàn-án 2021 láti gba ìjọba lọ́wọ́ Alpha Condé. Ní ọjọ́ tí ìdìtẹ̀ gba ìjọba náà ṣẹlẹ̀, Doumbouya kéde lórí ẹ̀rọ aṣọ̀rọ̀-má-gbèsì pé ìjọba ti tú ìjọba tẹ́lẹ̀ ká, ó tún kéde pé òfin ìlú náà ó dúró mọ́. NÍ ọjọ́ Kínní oṣù kẹwàá 2021, á kéde Doumbouya gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Guinea swears in coup leader Mamady Doumbouya as interim president". CNN. Reuters. October 2021. Archived from the original on 25 October 2021. Retrieved 10 August 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)