Mamluk Ali Nanautawi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iboji Mamluk Ali Nanautawi

Mamluk Ali Nanutawi, (èyí tí wọn tún máa ń pè ní Mamluk al-Ali Nanautawi) (tí wọ́n bí lójó keje oṣù kẹwàá ọdún 1789, tí ó ṣaláìsí lọ́dún 1851) jẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ Mùsùlùmí Súńní tí orílé èdè Índíà tí ó ṣíṣe-sìn gégé bí Adarí fún èdè Lárùbáwá ní Zakir Husain Delhi College [1]. Lára àwọn akékòó rẹ̀ ní: Muhammad Wasimi Nanautawi, Rashid Ahmad Gangohu àti Muhammad Yaqub Nanautawi.

Ibí àti Ètò Ẹ̀kọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mamluk Ali Nanautawi ní tí abí ni ọdún 1789 sí ìdílé Siddiqi FamilyNanauta.[2][3] A kò rí ohun tí ó pé lóri ètò ẹkọ aláàkọ bèrè ti Nanautawi. Wàyìó, wọ́n pé ó parí ìwé aláàkọ bèrè rẹ̀ lọ́wọ àwọn àgbàlagbà inú ẹbí ẹni. Nūr al-Hasan Rāshid Kāndhlawi lérò pé ẹ̀kọ́ rẹ̀ wá lábẹ́ ìmojutó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Nanautawi tí Mufti Ilaji Bakhsh tí orúkọ wón ń jẹ́ Abdur Rahman àti Abdur Raheem.[3] Ó sì parí ekó alákọ̀bẹ́rẹ́ labẹ́ Mufti Ilāhi Bakhsh Kāndhlawi àti Muhammad Qalandar Jalālābadi. Ó kọ̀ ẹ̀kó kan tí bá kò mọ̀ lọdọ Shah Abdul Aziz. Àlàyé mìíràn wá pé ó kó ẹ̀kọ́ labẹ́ Abdullah Khan Alvin. Ó sí parí ìmọ ẹ̀kọ́ gba gíga lábé Rasheed-ud-Dīn Khan.[4]

Iṣé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lèyìn tí o parí ẹkọ rè, Mamluk Ali bẹ́ẹ̀rẹ́ sí ní ṣe iṣé Olùkọ̀wé ní Delhi.[5] Ni osù kẹfa, ọdún 1825, wón Yàn sí pó láti di Olùkọní Àgbà ní ilé ẹkọ gíga Zakir Husain Delhi, wọ́n sí padà gbé sí ipò Adarí ni oṣù kọkànlá ní ọdún 1841.[6] Bákan náà ó ń ṣé iṣẹ Adarí fún ilé ẹkọ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀. Yàtọ̀ sí kíkọ àwọn rational science, èdè lárùbáwá,Fiqh, ọ tún kọ́bawon ìwé Sihah Sittah.[5] Ní ìbámu pẹlú Asir Adrawi, Nanautawi fí Gbogbo ojọ́ ayé tí ó fí ṣe iṣé Olúkóni ní Delhi. Àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n kan ní ìgbà náà tí wón jóọ́ kàwé tí wá ní àkọsílẹ[7]

Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn akékòó rẹ̀ ni:[8][9][10]

 • Muhammad Qasim Nanautawi, Olùdásílẹ̀ Darul Uloom Deoband
 • Syed Ahmad Khan, Olùdásílẹ̀ Aligarh Muslim University. [b]
 • Rashid Ahmad Gangohi, adájọ́ Hanafi.
 • Muhammad Yaqub Nanautawi, Adarí àkọ́kọ́ tí Darul Uloom Deoband.
 • Nazir Ahmad Dehlvi, Ẹni tí ó kọ́ ìwé eré-oníṣe Urdu .
 • Muhammad Mazhar Nanautawi
 • Ahmad Ali Saharanpuri, Ọ̀jọ̀gbọ́n Hadīth
 • Zulfiqar Ali Deobandi (Ọ̀kan lára àwọn olùásílẹ̀ Darul Uloom Deoband àti bàbá Mahmud Hasan Deobandi)
 • Fazlur Rahman Deobandi (Ọ̀kan lára Olùdásílẹ̀ Darul Uloom Deoband and father of Shabbir Ahmad Usmani)
 • Muhammad Munir Nanautawi ( Ààrẹ Ana ti Deoband)
 • Zakaullah Dehlvi

Ikú àti àwọn àṣesílẹ̀ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nanautawi kú ní ọjọ́ 7 oṣù October, ọdún 1851, wọ́n sì sin ín sí Munhadiyan, ní New Delhi, ní ẹ̀gbẹ́ sàárè Shah Waliullah Dehlawi.[11][12] Ọmọ rẹ̀ Muhammad Yaqub Nanautawi sìn gẹ́gẹ́ bí i adarí àkọ́kọ́ ti Darul Uloom Deoband.[13] Muhammad Qasim Nanautawi, tó jẹ́ olùdarí Darul Uloom Deoband máa ń ka àwọn ìwé rẹ̀ pẹ̀lú Mamluk Ali.[14] Khalil Ahmad Saharanpuri, tó jẹ́ òǹkọ̀wé Badhl al-Majhud, èyí tó jẹ́ àsọyé nípa Sunan Abu Dawud.[15]

Syed Ahmad Khan, tó jẹ́ olùásílẹ̀ Aligarh Muslim University gbóríyìn fun, ó sì sọ pé, "ẹ̀bùn ìrántí tí Mamlūk Ali ní jinlẹ̀ débi pé tí gbogbo ilé-ikàwé ní àgbááyé bá sọnù, Mawlāna á ṣàtúnkọ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan si, láti ọpọlọ rẹ̀."[16]

Àwọn itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Jones, K.W. (1992). Religious Controversy in British India: Dialogues in South Asian Languages. SUNY Series in Religious Studies. State University of New York Press. p. 180. ISBN 978-0-7914-0828-5. https://books.google.com.ng/books?id=whMLdd8F_xAC&pg=PA180. Retrieved 2022-07-02. 
 2. KZN 2020, p. 35.
 3. 3.0 3.1 Kāndhlawi 2000, p. 125.
 4. Kāndhlawi 2000, p. 127.
 5. 5.0 5.1 KZN 2020, p. 37.
 6. Kāndhlawi 2000, pp. 136–137.
 7. Adrawi 2016, p. 246.
 8. Khan, pp. 455-456.
 9. Rizwi 1980, pp. 73–75.
 10. Kāndhlawi 2000, p. 149.
 11. Kāndhlawi 2000, p. 150.
 12. KZN 2020, p. 40.
 13. Rizwi 1981, p. 126.
 14. Adrawi 2015, p. 59.
 15. Muhammad Zakariya Kandhalawi. "Hadhrat Aqdas Mawlāna al-Haaj Khalīl Ahmad" (in English). Tarikh-i Mashā'ikh-i Chisht. 
 16. KZN 2020, p. 38.