Mamman Daura
Mamman Daura Àdàkọ:Post-nominals | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1939 (ọmọ ọdún 84–85) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Trinity College Dublin |
Iṣẹ́ | Newspaper editor |
Gbajúmọ̀ fún | Leading Kaduna Mafia |
Mamman Daura (tí á bí ní ọdún 1939) jẹ́ olóòtù ìròyìn ti Nàìjíríà tí ó ṣé àtúnkọ, tí ó padà ṣe ìṣàkóso Nàìjíríà tuntun láti ọdún 1969 di 1975. Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí Ààrẹ Muhammadu Buhari[1] àti ọ̀kan gbòógì ọmọ ẹgbẹ́ Kaduna Mafia, ẹgbẹ́ aláìmúnisìn oníṣòwò, òṣìṣẹ́ ìlú, ọ̀jọ̀gbọ́n àti olórí ológún láti ilẹ̀-Àríwá Náìjíríà.[2][3][4]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Mamman Daura ní Daura, Ílè Aríwà, British Nigeria ní ọdún 1939,[5] bàbá rẹ̀ Alhaji Dauda Daura dì oyé Durbin Daura tí Daura Emirate;[6] ó sì jẹ́ ẹ̀gbọ́n Muhammadu Buhari.[7] Ó kẹ́ẹ̀kọ́ ní Daura Elementary School, Katsina Middle School kí ó tó lọ sí Provincial Secondary School, Okene. Ní ọdún 1956, nígbà tó pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, ó bẹ̀rẹ̀ síí ṣíṣẹ́ pẹ̀lú Daura Native Authority fún ọdún díẹ̀ kí ó tó dáràpọ̀ mọ́ Nigerian Broadcasting Corporation. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ilẹ̀-Àríwá mẹ́fà tí Sir Ahmadu Bello yàn láti kẹ́kọ̀ọ́ ní England
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ PADEN, JOHN N (2016) (in en). MUHAMMADU BUHARI;THE CHALLENGES OF LEADERSHIP IN NIGERIA. ROARING FORTIES PRESS. p. 7. ISBN 978-1938901683.
- ↑ Journalist, Naija (27 October 2019). "Mamman Daura: Facts about President Muhammadu Buhari's 'powerful nephew'". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 May 2020.
- ↑ Babah, Chinedu (10 November 2019). "DAURA,Mamman". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 May 2020.
- ↑ Daura, Fatima (9 November 2019). "Malam Mamman Daura: Tribute to Baba at 80!". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 15 December 2019. Retrieved 30 May 2020.
- ↑ Baiye, Clem (14 November 2019). "Mamman Daura at 80: A tribute". The Nation.
- ↑ "A tribute to Mamman Daura at 80". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 November 2019. Retrieved 9 August 2020.
- ↑ N. Paden, John (2016). Muhammadu Buhari: The Challenges of Leadership in Nigeria. pp. 7.