Jump to content

Mandazi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mandazi
Bowl of mandazi
Alternative namesSwahili Bun, Swahili Coconut Doughnut, bofrot, puff puff, mahamri/mamri (when made with coconut milk) [1]
Place of originSwahili Coast
Region or stateEast Africa (Tanzania, Kenya, Comoros, Uganda, Malawi,Rwanda, Burundi, Ethiopia, Somalia, South Sudan)[1]
Serving temperatureWarm or room temperature
Main ingredientsWater, sugar, flour, yeast, and milk (Coconut milk in mahamri or mamri)
VariationsVarious ingredients added such as coconut milk, peanuts, or almonds
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Mandazi (Swahili: Mandazi, Maandazi) jẹ́ ẹ̀yà búrẹ́dì kan tí orísun rẹ̀ jẹ́ Swahili Coast. Wọ́n mọ̀ ọ́n sí bofrot tàbí puff puff ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ń bẹ ní ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Áfíríkà bíi orílẹ̀-èdè Ghana àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúgbajà nínú àwọn oúnjẹ àwọn ènìyàn ilẹ̀ Swahili tí wọ́n sẹ̀ wá láti ẹkùn erékun orílẹ̀-èdè Kenya àti Tanzania.[2][3] Oúnjẹ yìí gbajúgbajà ní ẹkùn yìí, gẹ́gẹ́ bí ó ti rọrùn láti sè, tí ó sì rọrùn láti jẹ pẹ̀lú.[4][5]

Mandazi fi ara jọ doughnuts, tí ó ní àwọn òórùn aládìídùn èyí tí a le fi dá a mọ̀. Ṣùgbọ́n wọn kò dùn tó ti orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Amẹ́ríkà.[6] Wọ́n sáábà máa ń jẹ́ onígun mẹ́ta (tí ó fi ara pẹ́ samosa), ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ìgbà ni wọ́n máa ń rí roboto.[7] Wọ́n máa ń fẹ́lẹ́ lọ́wọ́ nígbà tí a bá sè wọ́n.

Bí a ṣe ń sè é

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Mandazi being fried

A máa ń se Mandazi díndín wọn pẹ̀lú òróró. Àwọn èròjà mandazi ni omi, súgà, ìyẹ̀fun, ìmúkàràwú, àti mílìkì. Bẹ́ẹ̀ ni a máa ń lo Mílìkì alágbọn láti mú kí ó dùn.[8][9] Bí wọ́n bá fi Mílìkì alágbọn sí mandazi, wọ́n sáábà máa ń pè é ní mahamri tàbí mamri.[10] Wọ́n gbajúgbajà ní ilẹ̀ Áfíríkà, tí wọ́n sì máa ń fi panu ṣáájú oúnjẹ òwúrọ̀.[4] A le jẹ́ Mandazi pẹ̀lú tíì tàbí ẹlẹ́rìndòdò.[11] Mandazi can also be eaten as a dessert after a meal where it is often served with powdered or cinnamon sugar to add sweetness.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


  1. 1.0 1.1 "Mandazi Doughnuts". Atlas Obscura. Retrieved 2019-06-11. 
  2. "MANDAZI : SWAHILI buzarelististBUNS". COOKS.COM. Retrieved 24 July 2014. 
  3. "Swahili Coconut Donuts ('Mandazi' in Swahili) Recipe". Family Cookbook Project. Retrieved 24 July 2014. 
  4. 4.0 4.1 Peck, Richard. "Swahili Recipes". Lewis & Clark. Archived from the original on 2010-02-27. Retrieved 2009-11-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. 5.0 5.1 "Kenyan Cookbook". Expanding Opportunities. Archived from the original on 2009-06-05. Retrieved 2009-11-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Mandazi Recipe". SparkRecipes. Retrieved 2009-11-13. 
  7. Kende, Eva. "Recipes (Mandazi)". Canadian eAuthors. Archived from the original on 2009-12-21. Retrieved 2009-11-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Jinsi ya Kupika Maandazi ya Nazi". Active Chef Issa Kapande. 28 May 2010. Retrieved 2014-02-05. 
  9. "MaandaziRecipe". Taste of Tanzania by Mariam Kinunda. Archived from the original on 2017-12-26. Retrieved 2014-02-05.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. Solomon Katz, ed. East Africa. Encyclopedia of Food & Culture. 1. Gale Cengage. http://www.enotes.com/food-encyclopedia/east-africa. Retrieved 2009-11-16. 
  11. "Sample Menu". Kitoweo. Archived from the original on 2010-11-30. Retrieved 2009-11-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Àdàkọ:African cuisine