Jump to content

Margaret Adeoye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Margaret Adeoye
Adeoye in the 400m heats at the Commonwealth Games 2014
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kẹrin 1985 (1985-04-22) (ọmọ ọdún 39)
Lagos, Nigeria[1]
Height1.76 m (5 ft 9 in)
Weight62 kg (137 lb)
Sport
Orílẹ̀-èdèIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)200 metres
ClubEnfield and Haringey Athletic Club
Coached byLinford Christie, Charles Van Commenee
Achievements and titles
Olympic finalsLondon 2012 (SF)
Personal best(s)22.88s

Margaret Adetutu Adeoye tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹrin ọdún 1985 [2] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Britain tó máa ń sáré nínú ìdíje eré-ìdárayá, tó sì máa ń kópa nínú ìdíje onígba mítà.Ó ṣojú ìlú Britain nínú ìdíje igba mítà ní ìlú London, ní ọdún 2012.[3]

Ìdíje rẹ̀ tó dára jù fún eré igba mítà wáyé ní ọjọ́ kẹfà oṣụ̀ kẹjọ, ọdún 2012, nígbà tí ó sá eré náà fún ìṣẹ́jú àáyá 22.94s, èyí sì mu kí ó kópa nínú ìdíje tó tẹ̀le.[4] Àmọ́ ó gbé ipò keje nínú ìdíje náà, kò sì lè tẹ̀síwájúsí ìpele tó kan. Ní ọdún 2013, ó sá eré igba mítà láàárín ìṣẹ́jú àáyá 22.88.[5]

Àwọn ìdíje agbáyé tí ó ti kópa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Aṣojú ìlú Britain
2013 World Championships Moscow, Russia 3rd 4 × 400 m relay 3:25:29
2014 World Indoor Championships Sopot, Poland 3rd 4 × 400 m relay 3:27.56
2015 World Championships Beijing, China 24th (sf) 200 m 23.34

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Margaret Adeoye - Athletics - Olympic Athlete | London 2012". Archived from the original on 2013-04-26. Retrieved 2014-02-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Margaret Adeoye". www.teamgb.com. Retrieved 5 July 2012. 
  3. "Enfield & Haringey Athletic Club's Margaret Adeoye joins Team GB for London 2012 Olympics". www.enfieldindependent.co.uk. 4 July 2012. http://www.enfieldindependent.co.uk/sport/9795384.Adeoye_selected_for_Team_GB/. Retrieved 5 July 2012. 
  4. "Sprint duo advance to Olympic semis". 
  5. "IAAF: Athlete profile for Margaret Adeoye". iaaf.org. Retrieved 2015-11-04.