Maria Najjuma
Center[1] | |
Personal information | |
---|---|
Born | 25 December 2003[2] |
Nationality | Ugandan |
Listed height | 6 ft 4 in (1.93 m) |
Maria Najjuma (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 2003) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Ugandan. Wọ́n pè é ní olùdíjebori ti 2019 FIBA U16 Women's African All-Star Five, nítorí ó pegedé nínú àwọn ìdíje tí ó kópa nínú pẹ̀lú Mariam Coulibaly, Maimouna Haidara, Sara Caetano àti Malak Sadek.[3][4]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n mú Najjuma wọ inú eré ìdárayá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n nígbà tí ó wà ní ọ̀dọ́. Àmọ́ nítorí ìpinnu rẹ̀ láti kàwé, wọ́n rán an lọ sí ìlé-ìwẹ́ Nations Changers Christian, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ tí ó sí ṣe ìdánwó. Ó tẹ̀síwájú láti lọ sí St. Noa girls secondary school, lẹ́yìn tó gba ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fé. Ibí sì ni Ugandan National team ti pè é láti kópa nínú ìdíje U16, tí ó sì gba pọ́ìntì ọgbọ̀n nínú ayò náà. Lẹ́yìn èyí, ó gba ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà USA, láti ìgbà náà sì ni ó ti ń ṣojú orílẹ́-èdẹ̀ rẹ̀ nínú ìdíje àárín ìlú àti ní àgbáyé.[5][6]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n pè Najjuma ní olùdíjebori ti 2019 FIBA U16 Women's African All-Star Five, nítorí ìkópa rẹ̀ nínú ìdíje náà àti yíyege tó yege. Èyí sì mu kí ó wọ NBA Academy Africa, láti fi kọ́ṣẹ́mọṣẹ́.[7][8][9]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Maria Najjuma, Basketball Player, News, Stats". Eurobasket LLC. Retrieved 2024-03-20.
- ↑ "Maria NAJJUMA at the FIBA U16 Women's African Championship 2019". FIBA.basketball. 2003-12-25. Retrieved 2024-03-20.
- ↑ Kawalya, Brian (2019-08-04). "FIBA Africa U16: Najjuma Wins Big As Uganda Finish Fifth". Live from ground (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-04-01.
- ↑ "Mali are #FIBAU16Africa 2019 Champions". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-04-14.
- ↑ "Maria Najjuma – Country Basketball Academy". Country Basketball Academy – Nurturing Talent. 2024-04-10. Archived from the original on 2024-04-19. Retrieved 2024-04-13.
- ↑ "Najjuma looks to leave mark at debut Uganda appearance". FIBA.basketball (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-04-14.
- ↑ "Uganda's Maria Najjuma selected for NBA Academy Camp – Federation of Uganda Basketball Associations" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-16. Retrieved 2024-03-20.
- ↑ Sports, Pulse (2023-02-04). "Former U16 star set to boost Uganda Gazelles camp". Pulse Sports Uganda. Retrieved 2024-04-13.
- ↑ "Coulibaly bags MVP at Women's #FIBAU16Africa 2019". FIBA.basketball. Retrieved 2024-04-13.