Mariam Kayode

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mariam Kayode
Ọjọ́ìbí1 June 2007
Oyo State
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Film actress

Mariam Kayode jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó bọ́ sí gbàgedè nígbà tó kópa nínú fíìmù kan tí akọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Children of Mud. Ó ti kópa nínú àwọn fíìmù bí i The Coffin Salesman, City of Bastards, àti Bayi.[1]

Ètò ẹ̀kọ́ àti ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni wọ́n bi sí ní 1 June 2007. Mariam kẹ́kọ̀ọ́ ní Kingsfield College, Ijede campus.[1]

Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òṣèrémọdé náà bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú fíìmù láti ìgbà èwe rẹ̀. Àwọn fíìmù bí i Children of Mud àti The Coffin Salesman ló mu gbajúmọ̀.[2]

Àwọn àtòjọ fíìmù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Dark Light (2015)
  • Happiness, Ltd (2016)
  • Don’t Leave Me (2016)
  • Children of Mud (2017)[1]
  • City of Bastards (2019)
  • The Coffin Salesman (2019)[2]
  • Price of Admission (2020)
  • Black Dove (2021)
  • Bayi[3]

Àwọn àmì-ẹ̀ye rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òṣèré tó dára jù ní eré kékeré ti Children of MudAMVCA 2018 awards.[4]

Òṣèrémọdé tó dára jù nínú fíìmù The Coffin Salesman fún BON award, 2018.[5]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 "Meet 11-year-old Mariam Kayode, first child actress nominated at AMVCA". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-09. Retrieved 2022-08-03. 
  2. 2.0 2.1 Webmaster (2018-09-02). "AMVCA nominee, 11, speaks: 'Acting'll just be a hustle, and Law my main career'". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03. 
  3. "Diane Russet Focuses on Underage Marriage – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-08-03. 
  4. Augoye, Jayne (2018-09-02). "#2018AMVCA: Bambam's outfit, Dino Melaye's 'movie nomination', other memorable moments". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-03. 
  5. Bada, Gbenga (2019-12-14). "BON Awards 2019: Nollywood stars gather for 11th edition in Kano". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-08-03.