Maureen Ihua
Ìrísí
Maureen Ihua
| |
---|---|
Bibi | Ipinle Rivers
|
Omo ilu | Nigeria |
Iṣẹ iṣe | Oṣere |
Awọn ọmọde | 5 |
Maureen Ihua jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bíi Domitila, Unplanned and Unpredictable. Ó ṣe fíìmù pẹ̀lú Liz Benson àti Regina Askia.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpínlẹ̀ Rivers ni Ihua ti wá, ó sì lọ sí ilé-ìwé girama ti Mariam Girls.[1]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ti ṣe ìfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà, tí iye rẹ̀ á máa lọ ọgọ́rùn-ún (100).[2]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Domitila
- The Millions
- Unpredictable
- Unplanned
- The Game
- Mama's big stick[3]
- Spirit of love
- Masked[4]
- Legend at 60[5]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ihua ti ṣe ìgbéyàwó, ó sì bí ọmọ márùn-ún.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ iliya, rejoice (2022-04-08). "Six Binge-Worthy Movies To Entertain You This Weekend". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "My movies demonstrate societal issues people shy away from – Sunny Okonkwo". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-14. Retrieved 2022-08-02.
- ↑ Augoye, Jayne (2018-01-08). "Davido stars in new Nollywood film". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-02.
- ↑ "Maureen Ihua: I Stopped Acting to Take Care of My Handsome Husband". www.thisdaylive.com. Archived from the original on 2022-08-02. Retrieved 2022-08-02.