Jump to content

Maurice Iwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Puffery

Maurice Mmaduakolam Iwu
3rd Chairman of the Independent National Electoral Commission
In office
June 2005 – 28 April 2010
AsíwájúAbel Guobadia
Arọ́pòAttahiru Jega
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kẹrin 1950 (1950-04-21) (ọmọ ọdún 74)
Umukabia, Ehime Mbano, Imo State, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
OccupationPharmacist
AwardsUS National Research International Prize for Ethnobiology (1999)

Maurice Mmaduakolam Iwu (wọ́n bí lọ́jọ́ 21 oṣù April ọdún 1950) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ ògùn ìwòsàn [pharmacognosy]] ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria. Òun ni alága àjọ ètò ìdìbò ní Nigeria, Independent National Electoral Commission (INEC) láti oṣù June ọdún 2005 sí oṣù April ọdún 2010.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The Chairman". Independent National Electoral Commission. Retrieved 2010-02-13.