Jump to content

May Ellen Mofe-Damijo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

May Ellen Ezekial Mofe-Damijo (1956 - 1996) tí a tún mọ̀ sí MEE[1] jẹ́ akọ̀ròyìn àti òǹkọ̀wé, tó ṣàtẹ̀jáde Classique magazine.[2] Ìwé-ìròyìn náà gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ akọ̀ròyìn bíi Dele Momodu, Ben Charles Obi, àti Rudolf Okonkwo.[3][4]

Mofe-Damijo tún kọ àwọn ìwé díẹ̀ bíi Dream maker àti Center Spread.

Àwọn ìwé àkọsílẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Classique Magazine | topetempler". topetempler.wordpress.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  2. "PENDULUM:Ovation International:20 years of celebrating Africa". The Boss Newspapers. 30 April 2016. Archived from the original on 23 January 2018. Retrieved 19 April 2023. 
  3. "The Lagos power list: 21 people in 21 million". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-22. Retrieved 2021-06-10. 
  4. "What You Don't Know About May Ellen Ezekiel, Richard Mofe-Damijo's First & Late Wife". ElorasBlog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-22. Retrieved 2021-08-23.