Mercedes-Benz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilé-iṣẹ́ Mercedes Benz ní Stuttgart, Germany
Mercedes-Benz
TypeDivision of Daimler AG
PredecessorBenz & Cie.
Daimler Motoren Gesellschaft
FoundedStuttgart, Germany (Oṣù Kẹfà 28, 1926 (1926-06-28))
Founder(s)Karl Benz
Gottlieb Daimler
HeadquartersStuttgart, Germany
Area servedWorldwide (except Mercedes-Benz vehicles and services with other distributors worldwide)
Key peopleDieter Zetsche (Head of Mercedes-Benz Cars Division)
IndustryAutomotive industry
ProductsAutomobiles
Trucks
Buses
Internal combustion engines
ServicesAutomotive financial services
ParentDaimler AG
Websitemercedes-benz.com

Mercedes-Benz (Pípè nì Jẹ́mánì: [mɛʁˈtseːdəs ˈbɛnts]) jẹ́ ilé-isé kan ní Jamini tí ó ń se oríṣiríṣi ọkọ̀. Mercedes-Benz wà lábé ilé-isé Daimler AG lọ́wọ́ lọ́wọ́ (ilé-isé tí a mọ̀ tẹ́lẹ̀rí sí DaimlerChrysler AG tàbí Daimler-Benz) Mercedes-Benz bẹ̀rẹ̀ nígbà Karl Benz ṣe ọkọ̀ àkọ́kọ́ tí ó ń lo epo petrol, ọkọ̀ Benz Patent Motorwagen.[1] àti bí Gottlieb Daimler àti Wilhelm Maybach ṣe sọ ọkọ̀ kan tí wọ́n má ń sọ mọ́ ẹṣin di ọkọ̀ tó ń lọ epo petrol. Daimler Motoren Gesellschaft ta ọkọ̀ Mercedes àkọ́kọ́ ní ọdun 1901. Wọ́n sì ṣe ọkọ̀ àkọ́kọ́ tí ó lórúko Mercedes-Benz lára jáde ní ọdun 1926, nígbà tí ilé-isé Karl Benz's àti Gottlieb Daimler para pò láti di ilé-isé Daimler-Benz.[1]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Mercedes-Benz History". Edmunds.com. Retrieved 2010-09-26.