Millennium Park (Abuja)
The Millennium Park jẹ́ pápá ìṣeré tí ó tóbi jù ní ìlú Abuja,[1][2][3] olú ìlú orilẹ-èdè Nàìjíríà, ó wà ní agbègbè Maitama nínú ìlú náà.
Ọbabìnrin Elizabeth kejì ni ó ṣe àfilọ́lẹ̀ pápá ìṣeré náà ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kejìlá ọdún 2003.[4][5][6] Ó sún mọ́ ilé ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Odò kan la pápá yìí kọjá, ó sì pín sí méjì. Apá kan pápá náà kún fún koríko àti igbó, ó sì tún jẹ́ ilé fún àwọn ẹyẹ àti labalábá. Apá kejì sún mọ́ ẹnu ọ̀nà àbáwọlé pápá náà, ó sì kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun àrà fún àwọn àlejò.
Ayàwòrán ilé ọmọ orílẹ̀ èdè Italy Manfredi Nicoletti ni ó ya àwọn ǹkan tí ó wà ní pápá yìí kí ó tó di pé wọ́n kọ,[7][8][9][10] pápá náà sì ti di ibi tí ọ̀pọ̀lopọ̀ àwọn ènìyàn láti Abuja fẹ́ràn láti ma wá.
Ara àwọn òtòkùlú tí ó wà níbi ifilọ́lẹ̀ pápá náà ni Olusegun Obasanjo, mínísítà àgbà orílẹ̀ èdè United Kingdom, Tony Blair àti Ọbabìnrin Elizabeth kejì.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Millennium Park (Abuja) – FCT Residents Engagement Platform" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-09-27. Retrieved 2022-11-25.
- ↑ Adebayo, Abdul Jelil (2022-08-07). "As Abuja Millennium Park reopens…". Blueprint Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-25.
- ↑ Liman, Hussein Yahaya, Dalhatu (2022-06-24). "Concerns over continued closure of Abuja Millennium Park". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-25.
- ↑ "Abuja minister reopens Millennium Park after two years shutdown" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-01. Retrieved 2022-11-25.
- ↑ "Abuja, Nigeria (1991- ) •" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-08-11. Retrieved 2022-11-25.
- ↑ "Millennium Park, Abuja, Abuja". Hotels.ng Places. Retrieved 2022-11-25.
- ↑ Adebayo, Abdul Jelil (2022-08-07). "As Abuja Millennium Park reopens…". Blueprint Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-25.
- ↑ "Millennium Park Abuja… A haven for leisure". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-05-21. Retrieved 2022-11-25.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Hotels.ng. "Millenium Park Abuja - With Love From Mother Nature". Hotels.ng Guides (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-25.
- ↑ People, Famous (2018-02-13). "Interesting Reasons You Should Visit The Millennium Park, Abuja". Famous People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-25.