Jump to content

Tony Blair

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tony Blair
Prime Minister of the United Kingdom
In office
2 May 1997 – 27 June 2007
MonarchElizabeth II
DeputyJohn Prescott
AsíwájúJohn Major
Arọ́pòGordon Brown
Leader of the Opposition
In office
21 July 1994 – 2 May 1997
Alákóso ÀgbàJohn Major
AsíwájúMargaret Beckett
Arọ́pòJohn Major
Member of Parliament
for Sedgefield
In office
9 June 1983 – 27 June 2007
AsíwájúNew Constituency
Arọ́pòPhil Wilson
Majority18,449 (44.5%)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Kàrún 1953 (1953-05-06) (ọmọ ọdún 71)
Edinburgh, Scotland
Ọmọorílẹ̀-èdèBritish
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLabour
(Àwọn) olólùfẹ́Cherie Booth
ẸbíWilliam Blair
Àwọn ọmọEuan, Nicholas, Kathryn, Leo
ResidenceConnaught Square
Alma materSt John's College, Oxford
OccupationEnvoy
ProfessionLawyer
SignatureFáìlì:Tony Blair signature.svg
WebsiteTony Blair Office

Anthony Charles Lynton "Tony" Blair (ọjọ́ìbí 6 May, 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Britani tó jẹ́ Alákòóso Àgbà orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Ìṣọ̀kan ti Britani Nínlá àti Irelandi Apáàríwá láti ọjọ́ 2 May ọdún 1997 títí di ọjọ́ 27 June ọdún 2007.