Minnatullah Rahmani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mawlāna

Minnatullah Rahmani
First General Secretary of All India Muslim Personal Law Board
In office
28 December 1972 – 20 March 1991
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí7 April 1913
Munger, British India
Aláìsí20 March 1991(1991-03-20) (ọmọ ọdún 77)
Àwọn ọmọWali Rahmani
BàbáMuhammad Ali Mungeri
Alma materDarul Uloom Nadwatul Ulama
Darul Uloom Deoband

Minnatullah Rahmani (Ni wọn bini ọjọ kèjè óṣu April, ọdun 1913 – ọjọ ògun, óṣu March ọdun 1991) jẹ́ ónimọ ẹsin musulumi sunni ti ilẹ India to jẹ akọkọ gbogbo akọwé ti igbimọ aladani ófin ti gbógbó musulumi ilẹ india[1]. Arakunrin naa jade ni Darul Uloom Nadwatul Ulama ati Darul Uloom Deoband pẹlu ọmọ ẹgbẹ iṣofin ijọ Bihar. Rahmani tun jẹ gbógbó akọwe fun Jamiat Ulama Bihar. Babà rẹ Muhammad Ali Mungeri jẹ óludasilẹ Nadwatul Ulama ti ọmọ rẹ, Wali Rahmani da ilè ẹkọ Rahmani30 silẹ.

Ìtan Minnatullah Rahmani[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Minnatullah Rahmani ni wọn bisi ilẹ Munger ni ọjọ kèjè, óṣu April, ọdun 1913[2] . Bara rẹ Muhammad Ali Mungeri jẹ óludasilẹ ti Nadwatul Ulama ni ilu Lucknow.[3].

Rahmani ṣè ẹkọ ibẹrẹ ni Munger to si lọ si Hyderabad lati kẹkọ lori ede larubawa pẹ̀lu Mufti Abd al-Lateef. Arakunrin naa kẹkọ ni Darul Uloom Nadwatul Ulama fun ọ̀dun mẹrin. Ni ọdun 1349 AH, o lọ si Darul Uloom Deoband nibi to ti kẹkọ pẹlu Ahmad Madani lori Sahih Bukhari to si jade ni ọdun 1352 AH[4]. Awọn ólukọ rẹ to ku ni Asghar Hussain Deobandi ati Muhammad Shafi Usmani[5].

Ni ọdun 1936, Rahmani jẹ gbógbó akọwe ti Jamiat Ulama Bihar[5]. Arakunrin naa jẹ̀ ọkan lara ọmọ ẹgbẹ Ẹgbẹ óminira musulumi eyi ti Abul Muhasin Muhammad Sajjad da silẹ ni ọdun 1935[5]. Arakunrin naa jẹ Sajjada Nashin ti Khanqah-e-Rahmani, Munger ni 1361 AH ati ikan lara ọmọ ẹgbẹ igbimọ Darul Uloom Deoband ni ọdun 1955, ipo to ṣiṣẹ fun titi ọjọ iku rẹ[6].

Pẹlu Muhammad Tayyib Qasmi, O kopa pataki ninu idasilẹ igbimọ ọfin gbógbó musulumi ilẹ India ti wọn si fi jẹ gbógbó akọwẹ akọkọ ni ibẹrẹ ipade naa ni ọjọ keji dinlọgbọn, óṣu December ni ọdun 1972[7].

Ni ọdun 1964, Arakunrin naa kopa ninu apèjọ gbogbó musulumi ágbàyè gẹgẹbi àṣoju ilẹ India. Ni ọdun 1945, Rahman tun Jamia Rahmania da silẹ, èyi to jẹ ilè kèwu to gbajumọ ni Munger, ilẹ India[2][8] He died on 20 March 1991.[9]. Arakunrin naa ku ni ọjọ ógun, óṣu March, ọdun 1991.

Ìpa àtijọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọmọkunrin Rahmani, Wali Rahmani da Rahmani30 silẹ to si tun fi igba kan jẹ gbógbó akọwè fun ifin aladani ti gbógbó musulumi ilẹ India[10][11]. Shah Imran Hasan kọ nipa itan ìgbèsi àyè rẹ Hayat-e Rahmani: Maulana Minnatullah Rahmani ki Zindagi ka Ilmi aur Tarikhi Mutala’a to ni ọrọ iṣààju lati ọdọ Akhtarul Wasey[12].

Awọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Amini, Noor Alam Khalil (February 2017). "Mawlāna Jalīl-ul-Qadar Aalim-o-Qā'id Amīr-e-Shariat: Hadhrat Mawlāna Sayyid Minatullah Rahmani - Chand Yaadein" [The Great Scholar and Leader, Amīr-e-Shariat: Hadhrat Mawlāna Sayyid Minatullah Rahmani - Few Memories]. Pas-e-Marg-e-Zindah (in Urdu) (5 ed.). Deoband: Idara Ilm-o-Adab. pp. 214–238.

  1. Azhar, Mohd. (2005). "Maulana Minnatullah Rahmani: analytical study of his life and religio_intellectual contributions". Aligarh. Retrieved 2023-09-14. 
  2. 2.0 2.1 Amini 2017, p. 237.
  3. Sayyid Muhammad al-Hasani (in Urdu). Sirat Hadhrat Mawlāna Sayyid Muhammad Ali Mungeri: Baani Nadwatul Ulama (4th, May 2016 ed.). Lucknow: Majlis Sahafat-o-Nashriyat, Nadwatul Ulama. "The relation has been discussed on page 334" 
  4. Rizwi, Syed Mehboob (1981). "Maulana Sayyid Minat Allah Rahmani". Tarikh Darul Uloom Deoband. 2. Deoband: Darul Uloom Deoband. pp. 121–123. 
  5. 5.0 5.1 5.2 Amini 2017, p. 234.
  6. Amini 2017, p. 238.
  7. Amini 2017, p. 217-218.
  8. "Munger's Jamia Rahmani holds its biennial contests for students". Two Circles. 2 April 2008. http://twocircles.net/2008apr02/munger_s_jamia_rahmani_holds_its_biennial_contests_students.html. Retrieved 27 August 2020. 
  9. Amini 2017, p. 214.
  10. "Officials of the AIMPLB". aimplboard.in. All India Muslim Personal Law Board. Retrieved 27 August 2020. 
  11. "Rahmani Mission President". www.rahmanimission.info. Retrieved 27 August 2020. 
  12. Mushtaq Ul Haq Ahmad Sikander (30 Jan 2013). "Book on Maulana Minnatullah Rahmani". The Milli Gazette. https://www.milligazette.com/news/13-books/6066-book-on-maulana-minnatullah-rahmani/. Retrieved 27 August 2020.